Malaki
ORI1
1ỌRỌỌRỌOluwasiIsraelinipaọwọMalaki.
2Emitifẹnyin,liOluwawi.Sibẹẹńsọpé,‘Níbonio fẹrànwa?EsaukohaṣearakunrinJakọbubi?liOluwawi: ṣugbọnemifẹJakobu.
3EmisikoriraEsau,mosisọawọnoke-nlarẹatiilẹ-inírẹ diahorofunawọnẹrankoijù
4.BiEdomusiwipe,Awaditalakà,ṣugbọnawaopada,a osikọibiahoro;bayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi,Nwọn okọ,ṣugbọnemiowólulẹ;nwọnosimapèwọnniàla ìwa-buburu,atiawọneniatiOluwabinusilailai.
5Ojunyinyiosiri,ẹnyinosiwipe,AogbéOluwagalati àgbegbeIsraeliwá
6Ọmọamabuọlafunbabarẹ,atiọmọ-ọdọfunoluwarẹ: njẹbiemibaṣebaba,ọlámida?biemibasiṣeolori,nibo niẹrumiwà?liOluwaawọnọmọ-ogunwifunnyin,ẹnyin alufa,tiogànorukọmi.Ẹyinsìwípé,“Níboniàwafi kẹgànorúkọrẹ?
7Ẹnyinfiàkaraaimọrubọloripẹpẹmi;ẹnyinsiwipe,Kili awafisọọdiaimọ?Ninueyiliẹnyinwipe,TabiliOluwa jẹẹgan
8Biẹnyinbasifiafọjurubọ,kòhaṣebuburu?bíẹbásìfi arọàtialáìsànrúbọ,kòhaburú?fifunbãlẹrẹnisisiyi;inu rẹyiohadùnsiọ,tabikioṣeojuṣajurẹ?liOluwaawọn ọmọ-ogunwi
9Njẹnisisiyi,emibẹnyin,ẹbẹỌlọrunkioleṣeore-ọfẹ funwa:nipaọwọnyinlieyitiri:onohakànyinsibi?li Oluwaawọnọmọ-ogunwi
10Tanininunyintioletiilẹkunlasan?bẹnikiẹnyinkio máṣedaináloripẹpẹmiliasanEmikoniinu-didunsi nyin,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,bẹliemikìyiogbaọrẹ lọwọnyin.
11Nitorilatiila-õruntitiofideiwọrẹ,orukọmiyiotobi lãrinawọnKeferi;atiniibigbogboliaofiturarisiorukọ mi,atiẹbọmimọ:nitoriorukọmiyiotobilãrinawọnkeferi, liOluwaawọnọmọ-ogunwi
12Ṣugbọnẹnyintibàajẹ,nitiẹnyinwipe,TabiliOLUWA diaimọ;atiesorẹ,anionjẹrẹ,jẹẹgan
13Ẹnyinsiwipe,Kiyesii,ãrẹkilio!ẹnyinsitirunsii,li Oluwaawọnọmọ-ogunwi;ẹnyinsimueyitiofàyawá,ati arọ,atiawọntioṣaisan;bayiliẹnyinmuọrẹwá:emioha gbàeyilọwọnyinbi?liOluwawi
14Ṣùgbọnègúnnifúnẹlẹtànnáà,tíóníakọnínúagboẹran rẹ,tíósìjẹjẹẹ,tíósìrúbọsíOlúwaohunìbàjẹ:nítoríèmijẹ ọbańlá,niOlúwaàwọnọmọ-ogunwí,ẹrùsìniorúkọmi láàrinàwọnorílẹ-èdè.
ORI2
1ÀTInísisìyí,ẹyinàlùfáà,òfinyìíwàfúnyín
" .ẹnikanyiosimunyinlọpẹlurẹ.
4Ẹnyinosimọpeemilioránofinyisinyin,kimajẹmu mikiolewàpẹluLefi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi
5Majẹmumisiwàpẹlurẹtiìyeatialafia;mosìfiwọnfún unnítoríẹrùtíófibẹrùmi,ẹrùsìbàáníwájúorúkọmi
6Ofinotitọmbẹliẹnurẹ,akòsiriẹṣẹlièterẹ:obamirìn lialafiaatiododo,osiyiọpọlọpọpadakuroninuẹṣẹ.
7Nitoripeètealufanikiopaìmọmọ,kinwọnkiosima wáofinliẹnurẹ:nitorionṣẹOluwaawọnọmọ-ogunniiṣe 8Ṣugbọnẹnyintiyàkuroliọna;ẹnyintimuọpọlọpọkọsẹ siofin;ẹnyintibamajẹmuLefijẹ,liOluwaawọnọmọogunwi
9Nítorínáà,èmináàtisọyíndiẹniẹgànàtiẹniẹgàn níwájúgbogboènìyàn,gẹgẹbíẹyinkòtipaọnàmimọ, ṣùgbọnẹńṣeojúsàájúnínúòfin
10Beemayinotọdopowẹmímẹpowẹyinya?Ọlọrun kankòhadawabi?ẽṣetiawafinhùwaarekereke olukulukusiarakunrinrẹ,nipasisọmajẹmuawọnbabawa dialaimọ?
11Judatihuwaarekereke,asitiṣeohuniriraniIsraeliati niJerusalemu;nitoriJudatisọìwa-mimọOluwadiaimọ,ti ofẹ,ositifẹọmọbinrinọlọrunajejikanniiyawo.
12Oluwayiokeọkunrinnatioṣeeyikuro,oloriati amoyekuroninuagọJakobu,atiẹnitioruọrẹ-ẹbọfun Oluwaawọnọmọ-ogun.
13Eyiliẹnyinsitunṣe,tiẹfiomijebòpẹpẹOluwa,pẹlu ẹkún,atipẹluigbe,tobẹtionkòfikàẹbọnasimọ,tabiki ofiinureregbàalọwọnyin.
14Ṣugbọnẹnyinwipe,Ẽṣe?NitoritiOLUWAtiṣeẹlẹri lãriniwọatiayaewerẹ,siẹnitiiwọtihùwaarekerekèsi: ṣugbọnonliẹlẹgbẹrẹ,atiayamajẹmurẹ.
15Onkòhasiṣeọkanbi?SíbẹóníìyókùẹmíAtiiditi ọkan?Kíólèwáirúgbìnoníwà-bí-ỌlọrunNítorínáà,ẹṣọ ẹmíyín,kíẹnikẹnimásìṣeàdàkàdekèsíayaìgbàèwerẹ.
16NitoriOluwa,ỌlọrunIsraeli,wipe,onkoriraikọsilẹ: nitoriẹnikanfiìwa-ipabòaṣọrẹ,liOluwaawọnọmọ-ogun wi:nitorinaẹṣọẹminyin,kiẹmábaṣearekereke 17ẸnyintifiọrọnyindaOLUWAliagaraSibẹẹńsọpé, “Níboniatidáalágara?Nigbatiẹnyinwipe,Olukuluku ẹnitionṣebuburu,odaraliojuOluwa,inurẹsidùnsiwọn; tabi,NiboliỌlọrunidajọwà?
ORI3
1Kiyesii,Emioránonṣẹmi,onositunọnaṣeniwajumi: Oluwa,tiẹnyinnwá,yiosiwásitempilirẹlojiji,anionṣẹ majẹmu,ẹnitiinunyindùnsi:wòo,onmbọ,liOluwa awọnọmọ-ogunwi.
2Ṣugbọntalioleduroliọjọwiwarẹ?atitaniyioduro nigbatiobafarahan?nítoríódàbíináolùyọmọ,àtibíọṣẹ apẹrẹ.
3Yóòsìjókòóbíẹnitíńyọfàdákàtíósìńwẹ:yóòsìwẹ àwọnọmọLéfìmọ,yóòsìwẹwọnmọgẹgẹbíwúrààti fàdákà,kíwọnlèmúọrẹwáfúnOlúwaníòdodo.
4Nigbanaliọrẹ-ẹbọJudaatiJerusalemuyiodùnsiOluwa, gẹgẹbitiigbãni,atibitiatijọ
5Emiosisunmọọfunidajọ;Emiosijẹẹlẹrikánkánsi awọnoṣó,atisiawọnpanṣaga,atisiawọnolufiraeke,ati siawọntinṣealagbaṣeliọyarẹlara,awọnopó,ati alainibaba,atiawọntioyialejòkuroninuẹtọrẹ,tinwọn kòsibẹrumi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi
6NitoriemiliOLUWA,emikòyipada;nítorínáàẹyin ọmọJakọbukòlèparun.
7Anilatiọjọawọnbabanyinliẹnyintiyapakuroninu ofinmi,ẹnyinkòsipawọnmọPadasimi,emiosiyipada sinyin,liOluwaawọnọmọ-ogunwi.Ṣugbọnẹnyinwipe, Ninukiniawaopada?
8ÈnìyànyóòhajaỌlọrunlólèbí?Síbẹẹyintijàmílólè Ṣugbọnẹnyinwipe,Ninukiliawafijaọ?Ninuidamẹwa atiawọnọrẹ
Malaki
9Egúnliafinyinbú:nitoritiẹnyintijàmiliolè,ani gbogboorilẹ-èdeyi.
11Emiosibaapanirunwinitorinyin,onkìyiosiruneso ilẹnyin;bẹniàjaranyinkiyiosoesorẹṣajuakokonioko, liOluwaawọnọmọ-ogunwi
12Gbogboorilẹ-èdeniyiosimapènyinlialabukúnfun: nitoriẹnyinojẹilẹdidùn,liOluwaawọnọmọ-ogunwi.
13Ọrọnyintilesimi,liOluwawiSibẹẹnyinwipe,Kili awasọrọpipọsiọ?
14Ẹnyintiwipe,AsannilatisìnỌlọrun:èrekiliosijẹti awatipailanarẹmọ,tiawasitirìnliọfọniwajuOluwa awọnọmọ-ogun?
15Atinisisiyiawanpèawọnagberagalialayọ;nitõtọ, awọntinṣiṣẹìwa-buburuliagbédide;nitõtọ,awọntio danỌlọrunwòniatigbala.
17Nwọnosijẹtemi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,liọjọ nanigbatimobaṣeohunọṣọmi;emiosidawọnsi,gẹgẹ bieniatindaọmọontikararẹsi
18Nigbanaliẹnyinoyipada,ẹnyinosimọlãrinolododo atieniabuburu,lãrinẹnitinsìnỌlọrunatiẹnitikòsìni.
ORI4
1Nitorikiyesii,ọjọmbọ,tiyiojobiileru;atigbogbo awọnagberaga,nitõtọ,atigbogboawọntinṣebuburu,ni yiodiakekùkoriko:ọjọtinbọyiosijówọnrun,liOluwa awọnọmọ-ogunwi,tikìyiofigbòngbotabiẹkasilẹfun wọn
2ṢugbọnfunẹnyintiobẹruorukọminiOorunododoyio làtiontiimularadaniiyẹ-aparẹ;ẹnyinosijadelọ,ẹnyin osidàgbabiọmọ-maluibùsọ
3Ẹnyinositẹawọneniabuburumọlẹ;nitoritinwọnodi ẽrulabẹatẹlẹsẹnyin,liọjọnatiemioṣeeyi,liOluwa awọnọmọ-ogunwi
4ẸrantiofinMoseiranṣẹmi,timopalaṣẹfununiHorebu fungbogboIsraeli,pẹluìlanaatiidajọ
5Kíyèsíi,èmiyóòránwòlíìÈlíjàsíọkíọjọńláàtiọjọẹrù Olúwatódé.
6Onosiyiọkànawọnbabapadasiọdọawọnọmọ,ati ọkànawọnọmọsiawọnbabawọn,kiemikiomábawafi aiyegégun.