ORI1
1ỌRỌOluwatiotọMikaaráMoratiwáliọjọJotamu, Ahasi,atiHesekiah,awọnọbaJuda,tiorinitiSamariaati Jerusalemu
2Ẹgbọ,gbogboẹnyinenia;fetisilẹ,iwọaiye,atiohun gbogbotimbẹninurẹ:sijẹkiOluwaỌlọrunkioṣeẹlẹrisi ọ,Oluwalatitẹmpilimimọrẹwá
3Nitorikiyesii,Oluwajadekuroniipòrẹ,yiosisọkalẹ, yiositẹibigigaaiyemọlẹ
4Awọnoke-nlayiosidididàlabẹrẹ,atiawọnafonifojili aolà,biidaniwajuiná,atibiomitiadàsilẹniibigiga.
5NitoriirekọjaJakobunigbogboeyi,atinitoriẹṣẹile IsraeliKíniìrékọjáJakọbu?ṢebíSamáríàni?atikini awọnibigigaJuda?ṢebíJerusalemuni?
6NitorinaemioṣeSamariabiòkitioko,atibigbigbin ọgba-àjara:emiosidàokutarẹlulẹsinuafonifoji,emiosi fiipilẹrẹhàn.
7Atigbogboerefifinrẹliaolùtũtu,atigbogboọyarẹlia ofiinásun,atigbogboererẹliemiosọdiahoro:nitoritio gbàalatiowoọyaaṣẹwó,nwọnosipadasiọyaaṣẹwó.
8Nítorínáàèmiyóòpohùnréréẹkún,èmiyóòsìpohùnréré ẹkún,Èmiyóòlọníìhòòhòàtiníìhòòhò:Èmiyóòsì pohùnréréẹkúnbíàwọnọrá,àtiọfọbíògòǹgò.
9Nitoripeọgbẹrẹkòlewosan;nitoritiodeJuda;otide ẹnu-bodeawọneniami,anisiJerusalemu
10.ẸmáṣesọọniGati,ẹmásisọkunrara:niileAfrayi ararẹkaninuerupẹ
11Ẹlọ,ẹyinaráSafiri,níìhòòhòìtìjúyínyiogbaidurorẹ lọwọrẹ.
12NitoritiawọnaraMarotundurodeire:ṣugbọnibisọkalẹ latiọdọOluwawásiẹnu-bodeJerusalemu.
13IwọolugbeLakiṣi,dikẹkẹmọẹrankotioyara:onni ipilẹṣẹẹṣẹfunọmọbinrinSioni:nitoritiariirekọjaIsraeli ninurẹ.
14NitorinaniiwọofiẹbunfunMoreṣeti-gati:awọnile AksibuyiojẹekefunawọnọbaIsraeli
15Ṣugbọnemiomuarolekantọọwá,iwọolugbeMareṣa: onowásiAdullamuogoIsraeli
16Paararẹpá,kiosirẹararẹkuronitoriawọnọmọẹlẹgẹ rẹ;múìpárírẹdipúpọbíidì;nitoritinwọnlọsiigbekun lọdọrẹ
ORI2
1EGBEnifunawọntingbiroẹṣẹ,tinwọnsinṣebuburu loriaketewọn!nigbatiilẹbamọ,nwọnaṣee,nitoritiowà liagbaraọwọwọn
2Nwọnsiṣojukokorooko,nwọnsifiagbaragbàwọn;ati ile,nwọnsikówọnlọ:bẹninwọnnienialoju,atiilerẹ,ani eniaatiinírẹ
3NitorinabayiliOluwawi;Kiyesii,siidileyiliemipète ibikan,ninueyitiẹnyinkiyioṣiọrùnnyinkuro;bẹni ẹnyinkògbọdọlọpẹluigberaga:nitoriakokoyibuburu
4Liọjọnaliẹnikanyiopaowesinyin,nwọnosi pohùnréreẹkunkikan,nwọnosiwipe,Atipawarun patapata:otiyiipínawọneniamipada:bawoniotimuu kurolọdọmi!lioyipadaliotipínokowa
5Nitorinaiwọkiyioniẹnikantiyiosọokùnnipakeké ninuijọOLUWA
6Ẹmásọtẹlẹ,ninwọnwifunawọntinsọtẹlẹ:nwọnkìyio sọtẹlẹfunwọn,kiojukiomábatìwọn
7IwọtianpèniileJakobu,ẹmiOluwahalebi?iṣerẹni wọnyi?ọrọmikòhaṣererefunẹnitinrindedebi?
8Aniliòpinawọneniamitididebiọta:ẹnyinfàaṣọawọn-aṣọkuroliọwọawọntinkọjaliailewu,bieniatio koriraogun.
9Awọnobinrineniamiliẹnyintiléjadekuroniile daradarawọn;liọwọawọnọmọwọnliẹnyintigbàogomi lailai.
10Ẹdide,kiẹsilọ;nitorieyikìiṣeisiminyin:nitoritiodi aimọ,yiosipanyinrun,anipẹluiparunkikan
11Biọkunrinkantinrinninuẹmiatiekebaṣeke,wipe, Emiosọtẹlẹfunọtiọti-wainiatiọtilile;onniyiosiṣe woliawọneniayi
12Nitõtọemiopejọ,Jakobu,gbogborẹ;Dájúdájú,èmi yóòkóàwọnìyókùÍsírẹlìjọ;Emiokowọnjọbiagutan Bosra,biagbo-ẹranlãrinagbowọn:nwọnohónlanitori ọpọlọpọenia.
13Ẹnitiofọgòkewásiwajuwọn:nwọntiya,nwọnsilà ẹnu-bodekọja,nwọnsijadelọdọrẹ:ọbawọnyiosikọja niwajuwọn,Oluwayiosiwàlioriwọn.
ORI3
1MOsiwipe,Gbọ,emibẹnyin,ẹnyinoloriJakobu,ati ẹnyinoloriileIsraeli;Kìhaṣefunọlatimọidajọ?
2Tiokorirarere,tinwọnsifẹbuburu;tíwọnjáawọwọn kúròlárawọn,atiẹranarawọnkúròníegungunwọn; 3Tinjẹẹran-araawọneniamipẹlu,tinwọnsijáawọwọn kurolarawọn;nwọnsifọegungunwọn,nwọnsigéwọn tũtu,bitiìkòkò,atibiẹranninuagbada
4NigbananinwọnokigbepèOluwa,ṣugbọnonkìyio gbọtiwọn:yiotilẹpaojurẹmọkurolarawọnliakokona, gẹgẹbinwọntihuwabuburunitiiṣewọn
5BayiliOluwawinitiawọnwolitinmuawọneniami ṣìna,tinwọnfiehinwọnbu,tinwọnsinkigbepe,Alafia; atiẹnitikòfisiẹnuwọn,aninwọnmuraogunsii
6Nitorinaoruyiojasifunnyin,tiẹnyinkìyiofiriiran; okunkunyiosiṣokunkunfunnyin,tiẹnyinkiyiofiṣe àfọṣẹ;òòrùnyóòsìwọlóríàwọnwòlíì,ọjọnáàyóòsì ṣókùnkùnlóríwọn. nitorikosiidahuntiOlorun
8ṢugbọnnitõtọemikúnfunagbaranipaẸmíOluwa,ati funidajọ,atifunipá,latisọirekọjaJakoburẹfun,atifun Israeliẹṣẹrẹ
9Emibẹnyin,ẹgbọeyi,ẹnyinoloriileJakobu,atiawọn ijoyeileIsraeli,tiokoriraidajọ,tiosinyigbogbootitọli aida
10NwọnfiẹjẹkọSioni,atiJerusalemupẹluẹṣẹ 11.Awọnoloriwọnnṣeidajọfunère,awọnalufarẹsima kọnifunọya,atiawọnwolirẹansọrọfunowo:sibẹnwọn ogbẹkẹleOluwa,nwọnosiwipe,Oluwakòhawàlãrinwa? buburukolewasoriwa.
12NitorinaliaoṣetulẹSioninitorinyinbioko, Jerusalemuyiosidiòkiti,atiòkenlailebiibigigaigbo
1“Ṣùgbọnníọjọìkẹyìnyóòsìṣe,aófiòkèiléOlúwakalẹ níoríàwọnòkèńlá,aósìgbéegajuàwọnòkèkékèkélọ; eniayiosimaṣànsiọdọrẹ.
2Ọpọlọpọorilẹ-èdeyiosiwá,nwọnosiwipe,Ẹwá,ẹjẹ kiagòkelọsiòkeOluwa,atisiileỌlọrunJakobu;Onosi kọwaliọnarẹ,awaosimarìnliipa-ọnarẹ:nitoriofinyio jadetiSioniwá,atiọrọOluwalatiJerusalemuwá
3Onosiṣeidajọlãrinọpọlọpọenia,yiosibaawọnorilẹèdealagbarawiliòkererére;nwọnosifiidàwọnrọabẹ itulẹ,atiọkọwọnrọọkọ-ọgbìn:orilẹ-èdekìyiogbeidà sokesiorilẹ-ède,bẹninwọnkìyiokọogunmọ.
4Ṣugbọnnwọnojokoolukulukulabẹàjararẹatilabẹigi ọpọtọrẹ;kòsìsíẹnitíyóòdẹrùbàwọn:nítoríẹnuOlúwa àwọnọmọ-ogunniótisọọ.
5Nitoripegbogboenianiyiomarìn,olukulukuliorukọ ọlọrunrẹ,awaosimarìnliorukọOluwaỌlọrunwalaiati lailai.
6Liọjọna,liOluwawi,emiokoawọntinkùnmọlẹjọ, emiosikóawọntialéjade,atiẹnitimotipọnloju; . 8Atiiwọ,ile-iṣọagbo-ẹran,odiagbaraọmọbinrinSioni, ọdọrẹniyiode,aniijọbaiṣaju;ijọbanayiodeọdọ ọmọbinrinJerusalemu.
9Njẹnisisiyiẽṣetiiwọfikigbesoke?kòhasiọbaninurẹ? ìgbimọrẹṣegbe?nitoriiroratimuọbiobinrintinrọbi .nibẹliaogbàọ;níbẹniOLUWAyóogbàọpadalọwọ àwọnọtárẹ
11Njẹnisisiyiọpọlọpọorilẹ-èdepejọsiọ,tinwọnwipe,Jẹ kiabàajẹ,sijẹkiojuwakiowòSioni.
12ṢugbọnnwọnkòmọìroOluwa,bẹninwọnkòmọìmọ rẹ:nitoritiyiokówọnjọbiitísinuipakà
13Dide,sipakà,iwọọmọbinrinSioni:nitoritiemiosọ iworẹdiirin,emiosisọpátákòrẹdiidẹ:iwọosigún ọpọlọpọeniatũtu:emiosiyàèrewọnsimimọfunOluwa, atiohuniniwọnfunOluwagbogboaiye.
ORI5
1Njẹnisisiyi,kóararẹliogun,ọmọbinrinogun:otidótì wa:nwọnofiọpálùonidajọIsraeliliẹrẹkẹ 2Ṣugbọniwọ,BetlehemuEfrata,biiwọtilẹjẹkekereninu ẹgbẹgbẹrunJuda,sibẹninurẹlionotijadetọmiwátiyio ṣeoloriniIsraeli;tíìjádelọrẹtiwàlátiìgbàláéláé,láti ayérayé.
3Nitorinayiofiwọnsilẹ,titidiigbatiẹnitinrọbiyiofibi: nigbananiiyokùawọnarakunrinrẹyiopadasọdọawọn ọmọIsraeli
4Onosiduro,yiosijẹunliagbaraOluwa,ninuọlanla orukọOluwaỌlọrunrẹ;nwọnosiduro:nitorinisisiyiono tobititideopinaiye.
5Ọkunrinyiyiosijẹalafia,nigbatiaraAssiriabadeilẹwa: nigbatiobasitẹãfinwamọ,nigbanaliawaogbéoluṣọagutanmejedidesii,atiọkunrinpatakimẹjọ
6NwọnosifiidàpailẹAssiriarun,atiilẹNimroduliẹnuọnarẹ:bẹlionogbàwalọwọawọnaraAssiria,nigbatio badeilẹwa,atinigbatiobatẹagbegbewamọ
7AwọniyokùJakobuyiosiwàliãrinọpọlọpọenia,biìrì latiọdọOluwawá,biọkọòjolorikoriko,tikòdurodè enia,tikòsidurodèawọnọmọenia
8AwọniyokùJakobuyiosiwàlãrinawọnKeferiliãrin ọpọlọpọeniabikiniunlãrinawọnẹrankoigbó,biọmọ kiniunlãrinagboagutan:ẹniti,biobalàjarẹkọja,tiotẹ mọlẹ,tiosiyatũtu,kòsisiẹnitiolegbà.
9Aogbéọwọrẹsokelaraawọnọtarẹ,gbogboawọnọta rẹliaosikekuro
10Yiosiṣeliọjọna,liOluwawi,liemiokeawọnẹṣinrẹ kurolãrinrẹ,emiosipakẹkẹrẹrun.
11Emiosikeawọniluilẹrẹkuro,emiosiwógbogboodi agbararẹlulẹ
12Emiosikeajẹkuroliọwọrẹ;ìwọkìyóòsìníàwọn aláfọṣẹmọ
13Èmiyóòkéàwọnèrefífínrẹkúrò,àtiàwọnèreìdúrórẹ kúròláàrinrẹ;iwọkìyiosisìniṣẹọwọrẹmọ
14Emiosifàere-oriṣarẹtukurolãrinrẹ:bẹliemiorun ilurẹ.
15Èmiyóòsìfiìbínúàtiìrunúgbẹsanláraàwọnorílẹ-èdè, irúèyítíwọnkòtíìgbọ
ORI6
1ẸgbọnisisiyiohuntiOLUWAwi;Dide,jàniwajuawọn òkenla,sijẹkiawọnòkekékèkégbọohùnrẹ
3Ẹyinènìyànmi,kínimoṣesíyín?atininukiliemitirẹọ liagara?jẹrisimi
4NitoripeemimúọgòkelatiilẹEgiptiwá,mosiràọpada kuroniileawọniranṣẹ;MosìránMósè,ÁrónìàtiMíríámù ṣáájúrẹ
5Ẹyinènìyànmi,ẹrántíohuntíBálákìọbaMóábùgbìmọ, àtiohuntíBálámùọmọBéórìdáalóhùnlátiṢítímùtítídé Gílígálì;kiẹnyinkiolemọododoOluwa
6KiliemiofiwásiwajuOluwa,tiemiofitẹaramiba niwajuỌlọrungiga?Èmiyóòhawásíwájúrẹpẹlúẹbọ sísun,pẹlúàwọnọmọmàlúùọlọdúnkan?
7InuOluwayiohadùnsiẹgbẹgbẹrunàgbo,tabisi ẹgbẹgbãrunodòororo?emiohafiakọbimifunirekọjami, atiesoaramifunẹṣẹọkànmi?
8Otifiohuntiodarahànọ,iwọenia;kiliOLUWAsi bèrelọwọrẹ,bikoṣelatiṣeododo,atilatifẹãnu,atilatiba Ọlọrunrẹrìnpẹluirẹlẹ?
9OhùnOluwakigbesiiluna,eniaọlọgbọnyiosiriorukọ rẹ:ẹgbọọpána,atitanioyàna.
10Iṣuraìwa-buburuhatunwàniileeniabuburu,ati òṣuwọnaikúntiiṣeirirabi?
11Kiemiohakàwọnsimimọpẹluòṣuwọnbuburu,ati pẹluàpoòṣuwọnẹtan?
12Nitoriawọnọlọrọinurẹkúnfunìwa-agbara,atiawọnti ngbeinurẹtisọrọeke,ahọnwọnsijẹẹtanliẹnuwọn
13Nitorinapẹluliemiomuọṣaisannililuọ,nisisọọdi ahoronitoriẹṣẹrẹ
14Iwọojẹ,ṣugbọniwọkìyioyó;atibiburẹyiosiwàli ãrinrẹ;iwọosimu,ṣugbọniwọkìyiogbà;atieyitiiwọo fisilẹliemiofiléidàlọwọ
15Iwọogbìn,ṣugbọniwọkìyioká;iwọotẹigiolifi, ṣugbọniwọkìyiofiorórokùnọ;atiọti-wainididùn, ṣugbọnkìyiomuọti-waini.
16NitoripeapailanaOmrimọ,atigbogboiṣẹileAhabu, ẹnyinsinrìnninuigbimọwọn;kiemikiolesọọdiahoro, atiawọntingbeinurẹdiẹgan:nitorinaliẹnyinoruẹgan eniami
1Egbénifunmi!nitoriemidabiigbatinwọnkóesoẹrun jọ,gẹgẹbieso-àjaratiàjara:kòsiiṣu-idilatijẹ:esoakọso liọkànmifẹ.
2Ènìyànreretiṣègbélóríilẹayé,kòsìsíolódodonínú ènìyàn:gbogbowọnlúgọdèẹjẹ;olukulukuwọnfiàwọn ṣọdẹarakunrinrẹ.
3Kinwọnkiolefiọwọmejejiṣebuburu,oloribère, onidajọsibereere;atienianla,osọrọìwa-ikarẹ:bẹni nwọnfidìi
4Ẹnitiodarajulọninuwọndabiẹwọn,oduroṣinṣinjulọli omújùọgbàẹgúnlọ:ọjọawọnoluṣọrẹatiibẹworẹmbọ; nisisiyiniidamuwọnyiojẹ
5Ẹmáṣegbẹkẹleọrẹkan,ẹmáṣegbẹkẹleamọnakan:pa ilẹkunẹnurẹmọkurolọwọẹnitiodubulẹliaiyarẹ.
6Nitoritiọmọṣealaibọlafunbaba,ọmọbinrindidesiiya rẹ,ayaọmọsiiyakọrẹ;àwọnọtáènìyànniàwọnaráilérẹ
7NitorinaliemiomawòOluwa;EmiodurodeOlorun igbalami:Olorunmiyiogbotemi
8Máṣeyọsimi,iwọọtami:nigbatimobaṣubu,emio dide;nigbatimobajokoliokunkun,Oluwayiojeimole funmi
9EmioruirunuOluwa,nitoritimotiṣẹsii,titiyiofi gbèjàmi,tiyiosiṣeidajọmi:yiomumijadewásiimọlẹ, emiosiriododorẹ
10Nigbanaliẹnitiiṣeọtámiyiorii,itijuyiosibòẹnitio wifunmipe,OLUWAỌlọrunrẹdà?ojumiyiorii: nisisiyiliaotẹọmọlẹbiẹrẹita
11Liọjọnatiaomọodirẹ,liọjọnaliaṣẹnayiojinarére
12Liọjọnapẹlu,yiositọọwálatiAssiria,atilatiilu olodi,atilatiodititideodò,atilatiokundeokun,atilati òkedeòke
13Ṣugbọnilẹnayiodiahoronitoriawọntingbeinurẹ, nitoriesoiṣewọn
15GẹgẹbiọjọtiiwọtiilẹEgiptijadewá,emiofiohun iyanuhànfunu
16Awọnorilẹ-èdeyiori,ojuyiositìwọnnitorigbogbo agbarawọn:nwọnofiọwọleẹnuwọn,etiwọnyiodiaditi.
17Nwọnoláerupẹbiejò,nwọnosijadekuroninuihò wọnbikòkoroilẹ:nwọnobẹruOluwaỌlọrunwa,nwọno sibẹrunitorirẹ.
18TaniỌlọrunbiiwọ,tiondariẹṣẹjì,tiosikọjanipa irekọjaiyokùinírẹ?kòdaibinurẹdurolailai,nitoritioṣe inu-didùnsiãnu.
19Onoyipada,yiosiṣãnufunwa;òunyóòsìṣẹgunàwọn ẹṣẹwa;iwọosisọgbogboẹṣẹwọnsọsinuọgbunokun.
20IwọoṣeotitọfunJakobu,atiãnufunAbrahamu,tiiwọ tiburafunawọnbabawalatiigbaatijọwá