Grandma Funeral Brochure

Page 1

Officiating Ministers

1. Pastor (Dr) M.K Ehinmode (Amuse Odofin DCC Superintendent)

2. Pastor S.O Akanmu (Apata Zonal Superintendent)

3. Pastor I.O Afolayan (Christ Family Zonal Superintendent)

4. Pastor J.T Omoniyi (Agbala Imuse Ayo District Superintendent)

5. Pastor J.A Akinbobola

6. Pastor I.A Asimolowo

Elder Bolarinwa Choirmaster

Pastor S.O. Akanmi

Apata Zonal Superintendent

Pastor E.E. Mapur

Cac Gen. Sec. Nigeria And Overseas

Pastor E.O. Odejobi

Bro Samuel Omoniyi Organist

Pastor G.S. Dada Regional Superintendent

Prophet Hezekiah O. Oladeji

Gen. Evang. CAC Nigeria and Overseas

Gen. Superintendent, CAC Nigeria and Overseas

Pastor S.O. Oladele

President CAC Nigeria and Overseas

Service at Home Grave-Side Order of Service Thanksgiving Service Eto Isinku L’eti Iboji Eto Dupe Isinku 1. Orin Ibere - CAC GHB 329 2. Adura 3. Eko Kika - 1Tess. 4:13-18 4. Oro Iyanju 5. Adura 6. Ifilo 7. Orin Ipari Isin - CAC GHB 975 8. Oore-Ofe 1. Orin Ibere - CAC GHB 967 2. Jesu Wipe 3. Eko Kika - Orin Dafidi 90:1-14 4. Gbigbe Oku Si Isa 5. Bibu Erupe 6. Mo Gbo Ohun Kan Lati Orun Wa 7. Adura 8. Orin Ipari Isin - CAC GHB 935 9. Oore-Ofe 1. Orin Ibere - CAC GHB 327 2. Adura 3. Eko Kika 4. Orin Adako 5. Iwaasu 6. Adura Lehin Iwaasu 7. Adura fun Ebi Oloogbe 8. Idupe Ijade Oku 9. Ifilo 10. Oro Idupe 11. Orin Ipari Isin - CAC GHB 963 12. Adura 13. Oore-Ofe 1. Opening Hymn - CAC GHB 329 2. Prayer 3. Bible Reading - 1Thess. 4:13-18 4. Exhortation 5. Prayer 6. Announcement 7. Closing Hymn - CAC GHB 975 8. Benediction 1. Opening hymn - CAC GHB 967 2. Jesus Said 3. Bible Reading - Psalm 90:1-14 4. Lowering Corpse Into Grave 5. Committal 6. I heard A Voice From Heaven 7. Prayer 8. Closing Hymn - CAC GHB 935 9. Benediction 1. Opening Hymn - CAC GHB 327 2. Prayer 3. Bible Reading 4. Special Rendition 5. Sermon 6. Prayer after Sermon 7. Prayer for the Family of the Deceased 8. Thanksgiving 9. Announcement 10. Vote of Thanks 11. Closing Hymn - CAC GHB 963 12. Prayer 13. Benediction ETO ISIN ISINKU (ORDER OF FUNERAL SERVICE) Isin ti inu ile

1. Orin Ibere (Opening Hymn)

ORIN 329 - JESU YE TITI AYE

1. Jesu ye titi aye, Eru iku ko ba mi mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n’ipa mo Aleluya.

2. Jesu ye, lat’oni lo, Iku je ona s iye;

Eyi y’o je ‘tunu wa ‘Gbat’akoko iku ba de Aleluya.

3. Jesu ye; fun wa lo ku, Nje Tire, ni a o ma se;

A o f’okan funfunsin, A o f’ogo f’Olugbala Aleluya.

4.Jesu ye; eyi daju, Iku at’ipa okunkun

Ki yo le ya ni kuro

Ninu ife nla ti Jesu Aleluya.

5.Jesu ye; gbogbo ‘joba L’orun, li aye, di Tire; E je ki a ma tele, Ki a le jona pelu Re Aleluya.

2. Adura (Prayer)

Amin.

HYMN 329 - JESUS LIVES!

1. Jesus lives! thy terrors now Can, O death, no more appal us, Jesus live! by this we know Thou, O grave, canst not enthral us Hallelujah!

2. Jesus lives! henceforth is death

Entrance-gate of life immortal; This hall calm our trembling breath

When we pass its gloomy portal, Hallelujah!

3. Jesus lives! for us He died; Hence may we, to Jesus living Pure in heart and act abide, Praise to Him and glory giving, Hallelujah!

4. Jesus live! our hearts know well Nought from us His love shall sever, Life, nor death, nor pow’rs of hell, Part us now from Christ for ever, Hallelujah!

5. Jesus lives! to Him throne

High o’er heav’n and earth is given; We may go where He is gone, Live and reign with Him in heaven. Hallelujah!

Amen

3. Eko Kika (Bible Reading)

1 TẸSALONIKA 4:13-18

13 Ẹ̀yin ará, àwa kò fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó jẹ́ òpè ní ti àwọn tí ó ti sùn, pé kí ẹ máa banújẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn yòókù tí kò ní ìrètí.

14 A gbàgbọ́ pé, Jesu kú, ó sì tún jínde, àti pé Ọlọ́run yóò mú gbogbo àwọn tí ó ti sùn nínú rẹ̀ padà wá.

15 Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa, pé àwa tí ó wà láààyè, tí a sì kù lẹ́yìn de à ti wá Olúwa, bí ó ti wù kí ó rí, kì yóò ṣáájú àwọn tí ó sùn láti pàdé rẹ̀.

16 Nítorí pé, Olúwa fúnrarẹ̀ yóò sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá, pẹ̀lú ariwo àṣẹ ńlá àti ohùn àwọn angẹli ti àwọn angẹli ti àwọn ti ìpè Ọlọ́run, àwọn òkú nínú Kristi yóò sì kọ́kọ́ jínde.

17 Nígbà náà ni a ó gba àwa tí ó sì wà láààyè sókè nínú àwọsánmọ̀ láti ọwọ́ Olúwa. A ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀ títí láéláé.

18 Nítorí náà, ẹ tu ara yín nínú, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.

1 THESSALONIANS 4:13-18

13 But I would not have you to be ignorant, brethren, concerning them which are asleep, that ye sorrow not, even as others which have no hope.

14 For if we believe that Jesus died and rose again, even so them also which sleep in Jesus will God bring with him.

15 For this we say unto you by the word of the Lord, that we which are alive and remain unto the coming of the Lord shall not prevent them which are asleep.

16 For the Lord himself shall descend from heaven with a shout, with the voice of the archangel, and with the trump of God: and the dead in Christ shall rise first:

17 Then we which are alive and remain shall be caught up together with them in the clouds, to meet the Lord in the air: and so shall we ever be with the Lord.

18 Wherefore comfort one another with these words.

4. Oro Iyanju (Exhortation)

5. Adura (Prayer)

6. Ifilo (Announcement)

7. Orin Ipari Isin (Closing Hymn)

ORIN 975 - AO PADE

L’ETI ODO

1. Ao pade l’eti odo

T’ese angeli ti te.

Tt’o mo gara bi Kristali

L’eba ite Olorun.

A o pade l’eti odo didan

Odo didan , odo didan na.

Tt’o nsan l’eba ite ni.

2. L’eti bebe odo na yi

Ao r’oju Olugbala;

Emi wa ki o si pinya mo;

Yio korin ogo Re.

3. Nje l’eba odo tutu na,

Ao r’oju Olugbala;

Emi wa ki yio pinya mo

Yio korin ogo Re.

4. K’a to de odo didan na, A o s’eru wa kale.

Jesu y’o gba eru ese;

Awon ti O de l’ade

5. A fe de odo didan na, ‘Rin ajo wa fere pin;

Okan wa kun f’orin

Ayo at’ Alafia. Amin.

8. Oore-Ofe (Benediction)

HYMN 975 - SHALL WE GATHER AT THE RIVER

1. Shall we gather at the river

Where bright angel feet have trod; With its crystal tide for ever Flowing by the throne of God!

Yes, we’ll gather at the river, The beautiful, beautiful river; Gather with the saints at the river. That flows by the throne of God.

2. On the margin of the river, Guided by our Shepherd King, We will walk and worship ever, His dear footsteps following.

3. There beside the tranquil river, Mirror of the saviour’s face, Happy hearts, no more to sew, Sing of glory and of grace.

4. But before we gain the river, Lay we every burden down; Jesus, here from sin deliver, Those whom there Thy grace will crown.

5. Soon we’ll reach the crystal river; Soon our pilgrimage will cease; Soon our golden harpstrings quiver, With the melody of peace. Amen.

1. Orin Ibere (Opening Hymn)

ORIN 967 - A NSORO ILE ‘BUKUN NI

1. A nsoro ile ‘bukun ni, Ile didan at’ ile ewa.

‘Gbagbogbo l’a nso t’ogo re.

Y’o ti dun to lati de be.

2. A nsoro ita wura Re. Oso odi re ti ko l’egbe, ‘Faji re ko se f’enu so

Y’o ti dun to lati de be,

3. A nso p; ese ko si nibe. Ko s’aniyan at’ ibanuje, elu ‘danwol’ode , ninu; T’o ti dun lati de be,

4. A nsoro orin iyin re. Ti a kole f’orin aye we.

B’o ti wu k’orin wa dun to. Y’o ti dun to lati de be,

5. A nsoro isin ife re.

Ti agbada t’awon mimo nwo. Ijo akobi ti oke; Y’o ti dun to lati de be.

6. Jo Oluwa l’onakona, Sa emi wa ye fun orun.

Laipe awa na yio mo, B’ o ti dun to lati de be, Amin

HYMN 967 - WE SPEAK OF THE REALMS OF THE BLEST

1. We speak of the realms of the Blest, Of that country so bright and so fair, And oft are its glories confess’d; But what must it be to be there?

2. We speak of its pathway of gold, Of its walls deck’d with Jewels most rare Its wonders and pleasures untold But what must it be to be there?

3. We speak of its freedom from sin, From sorrow, temptation, and care, From trials without and within? But what must it be to be there?

4. We speak of its anthems of praise, With which we can never compare The sweetest on earth we can raise; But what must it be to be there?

5. We speak of its service of love, Of the robes which the glorified wear, The Church of the First-born above, But what must it be to be there?

6. Do Thou, Lord, ‘midst pleasure of woe, Still for Heav’n our spirits prepare; And shortly we also shall know And feel what it is to be there. Amen.

2. Jesu Wipe (Jesus Said)

Èmi ni àjínde àti ìyè: ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, bí ó tilẹ̀ kú, yóò yè:

Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín kí ó dàrú: ẹ gba

Ọlọ́run gbọ́, kí ẹ sì gbà mí gbọ́ pẹ̀lú. Nínú ilé Baba mi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibùgbé ni ó wà: ìbá má ṣe bẹ́ẹ̀, èmi ìbá tí sọ fún yín.

Nítorí èmi mọ̀ pé olodùmarè mi ń bẹ láààyè àti pe òun ni yóò dìde dúró lórí ilẹ̀ ní ìkẹyìn; Àti lẹ́yìn ìgbà tí a pa àwọ̀ ara mi run, síbẹ̀ láìsí ẹran-ara mi ni èmi ó rí Ọlọ́run, Ẹni tí èmi ó rí fún ara mi, tí ojú mi ó sì wo, kì sì í ṣe ti ẹlòmíràn;

A kò mú ohun kan wá sí ayé, bẹ́ẹ̀ ni a kò sì lè mu ohunkóhun jáde lọ.

Olúwa fi fún ni, Olúwa sì gbà á lọ, ìbùkún ni fún orúkọ Olúwa.”

I am the resurrection, and the life: he that believeth in me, though he were dead, yet shall he live:

Let not your heart be troubled: ye believe in God, believe also in me. In my Father’s house are many mansions: if it were not so, I would have told you. I go to prepare a place for you.

For I know that my redeemer liveth, and that he shall stand at the latter day upon the earth: And though after my skin worms destroy this body, yet in my flesh shall I see God: Whom I shall see for myself, and mine eyes shall behold, and not another;

For we brought nothing into this world, and it is certain we can carry nothing out.

The Lord gave, and the Lord hath taken away; blessed be the name of the Lord.

3. Eko Kika (Bible Reading)

ORIN DAFIDI 90:1-17

1 Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìran dé ìran.

2 Kí a tó bí àwọn òkè ńlá àti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé, láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run.

PSALM 90:1-17

1 Lord, thou hast been our dwelling place in all generations.

2 Before the mountains were brought forth, or ever thou hadst formed the earth and the world, even from everlasting to everlasting, thou art God.

3 Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀, wí pé “Padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn.”

4 Nítorí pé ìgbà tí ẹgbẹ̀rún ọdún bá kọjá lójú rẹ, bí àná ni ó rí, bí ìgbà ìṣọ́ kan lóru.

5 Ìwọ gbá ènìyàn dànù nínú oorun ikú; wọ́n dàbí koríko tuntun ní òwúrọ̀.

3 Thou turnest man to destruction; and sayest, Return, ye children of men.

4 For a thousand years in thy sight are but as yesterday when it is past, and as a watch in the night.

5 Thou carriest them away as with a flood; they are as a sleep: in the morning they are like grass which groweth up.

6 Lóòtítọ́, ní òwúrọ̀, ó yọ tuntun ní àṣálẹ́ ni yóò gbẹ, tí yóò sì rẹ̀ dànù.

7 A pa wá run nípa ìbínú rẹ nípa ìbínú rẹ ara kò rọ̀ wá.

8 Ìwọ ti gbé ẹ̀ṣẹ̀ wa ka iwájú rẹ, àti ohun ìkọ̀kọ̀ wa nínú ìmọ́lẹ̀ iwájú rẹ,

9 Gbogbo ọjọ́ wa ń kọjá lọ lábẹ́ ìbínú rẹ; àwa ń lo ọjọ́ wa lọ bí àlá tí à ń rọ́.

10 Àádọ́rin ọdún ni iye ọjọ́ ọdún wá, bi ó sì ṣe pé nípa agbára tí wọn bá tó

ọgọ́rin ọdún, agbára nínú làálàá pẹ̀lú ìbànújẹ́ ni, nítorí pé a kò ní pẹ́ gé e kúrò, àwa a sì fò lọ.

11 Ta ni ó mọ agbára ìbínú rẹ? Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rù rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ìbínú rẹ.

12 Kọ́ wa bí a ti ń kaye ọjọ́ wa dáradára, kí àwa ba à lè fi ọkàn wa sípa ọgbọ́n.

6 In the morning it flourisheth, and groweth up; in the evening it is cut down, and withereth.

7 For we are consumed by thine anger, and by thy wrath are we troubled.

8 Thou hast set our iniquities before thee, our secret sins in the light of thy countenance.

9 For all our days are passed away in thy wrath: we spend our years as a tale that is told.

10 The days of our years are threescore years and ten; and if by reason of strength they be fourscore years, yet is their strength labour and sorrow; for it is soon cut off, and we fly away.

11 Who knoweth the power of thine anger? even according to thy fear, so is thy wrath.

12 So teach us to number our days, that we may apply our hearts unto wisdom.

13 Yípadà, Olúwa! Yóò ti pẹ́ tó? Ṣàánú fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ.

14 Tẹ́ wa lọ́rùn ní òwúrọ̀ nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ, kí àwa kí ó lè kọrin fún ayọ̀ kí inú wa sì dùn ní gbogbo ọjọ́.

15 Mú inú wa dùn bí ọjọ́ tí ìwọ ti pọ́n wa lójú, fún ọjọ́ púpọ̀ tí àwa ti rí wàhálà.

16 Jẹ́ kí a fi iṣẹ́ rẹ̀ han àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀, ògo rẹ̀ sí àwọn ọmọ wọn.

17 Jẹ́ kí ẹwà Olúwa Ọlọ́run wa wà lára wa; fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀ lára wa bẹ́ẹ̀ ni, kí ó sì fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀.

13 Return, O Lord, how long? and let it repent thee concerning thy servants.

14 O satisfy us early with thy mercy; that we may rejoice and be glad all our days.

15 Make us glad according to the days wherein thou hast afflicted us, and the years wherein we have seen evil.

16 Let thy work appear unto thy servants, and thy glory unto their children.

17 And let the beauty of the Lord our God be upon us: and establish thou the work of our hands upon us; yea, the work of our hands establish thou it.

4. Gbigbe Oku Si Isa (Lowering Corpse into the Grave

Alufa yi o wipe:

Enia ti a bi ninu obirin, ojo kukuru sa li o ni igbe aiye, o si kun fun osi, o ndagba soke, a si ke e lule, bi itana eweko; a rekoja lo bi ojiji, lai ko duro nini kan. Li arin iye, awa mbe ninu iku, lodo tali awa o ha ma wa iranwo bikose lodo re, Oluwa, eniti o ti tori ese wa jare lati binu.

Sugbon, Oluwa Olorun mimo julo, alagbara julo, Olugbala mimo ati alanu julo, ma fi wa sinu irora kikoro iku ti ko nipekun.

Oluwa, o mo ohun ikoko okan wa; mase di eti enu re si adura wa; sugbon Oluwa mimo ati alanu julo, da wa si, eniti O ye julo, li onidajo aiyeraye, li opin wakati wa nitori irora kirora iku ma je ki a subu kuro lodo Re. Amin.

The Pastor shall say:

Man that is born of woman is of few days, and full of trouble. He comes forth like a flower, and withers; He flees like a shadow and continues not. In the midst of life, we are in death. Of whom may we seek for succor, but of thee O Lord, who for sins are jusily displeased? Yet O Lord Most High, O Lord Most Mighty, O Holy and Most Merciful Saviour, deliver us not into the bitter pains of eternal death.

Thou knows, Lord, the secrets of our hearts, shut not Thy merciful ears to our prayers. Spare us, Lord most holy, O God most mighty, O Holy and merciful Saviour, Thou most worthy judge eternal, suffer us not, at last hour, because of any pains of death, to fall from Thee. Amen.

5. Bibu Erupe (Committal)

Alufa yi o wipe:

Nje bi o ti wu Olorun Olodumare ninu anu re nla, lati gba iranse re yi owon Evangelist (Mrs.) Victoria Oyenike

Adegoke ti o ti ihin sile lo, sodo ara re, nitorina awa fi oku re fun ile; erupe fun erupe; eeru fun eeru; ni idaniloju ati li aisiyemeji ireti ajinde siiye ti ko nipekun, nipa Oluwa wa Jesu Kristi; eniti yi o pa ra ara osi wa da, ki o le ri bi ara on tikarare ti o logo, gegebiise agbara, nipa eyi ti on le fi teri ohun gbogbo ba fun ara re.

The Pastor shall say:

Forasmuch as it had pleased the Almighty God in His wise providence to take out of this world the soul of our deceased Evangelist (Mrs.) Victoria Oyenike Adegoke. We therefore commit this body to the ground; earth to earth, ashes to ashes, dust to dust; in sure and certain hope of the resurrection in the last day, and the life of the world to come; through our Lord Jesus Christ; at whose second coming in glorious majesty to judge the world, the earth and the sea shall give up their dead and the corruptible bodies for those who sleep in Him shall be changed, and made like unto His own glorious body according to the mighty working whereby He is able to subdue all things unto Himself

6. Mo Gbo Ohun Kan Lati Orun Wa (I Heard A Voice From Heaven)

Alufa yi o wipe:

Mo gbo ohun kan lati orun wa ti nwi fun mi pe, kowe re lati isisiyi lo, alabukun ni fun awon oku ti o ku ninu Oluwa; beeni Emi nwi nitori nwon simi kuro ninu laalaa won. Nitori ise won nto won lehin.

7. Adura

8. Orin Ipari Isin (Closing Hymn)

ORIN 935 - MA SUN , OLUFE; K’O SIMA SIMI

1. Ma sun , olufe ; k’o sima simi

Gb’ ori re le aya Olugbala

A fe o sugbon Jesu fe o ju. Sun ‘re sun ‘re sun re.

The Pastor shall say:

And I heard a voice from heaven saying unto me, Write, Blessed are the dead which die in the Lord from henceforth: Yea, saith the Spirit, that they may rest from their labours; and their works do follow them.

HYMN 935 -SLEEP ON, BELOVED, SLEEP AND TAKE THY REST

1. Sleep on, beloved, sleep and take thy rest; Lay down thy head upon thy Saviour’s breast; We love thee well; but Jesus loves thee best. Good-night! Good-night! Good-night!

2. Orun re dun bi orun omode,

Iwo ki yo si ji si ekun mo.

Isimi t’o daju n’ismi re.

Sun ‘re sun ‘re sun ‘re.

3. Tit’ ao ka okunkun aye kuro

Tit’ ao fi ko ikore ‘wole

Tit’ oye yio fi la,

Sun ‘re sun ‘re sun ‘re

4. Tit’ orun ajinde y’o fi yo

T’awon oku n’nu Jesu y’o dide

On y’o si wa ninu olanla Re.

Sun ‘re sun ‘re sun’re.

5. Tit’ ewa orun y’o je tire

Ti iwo o ma ran ninu ogo

Oluwa y’o de o l’ade wura.

Sun’re sun’re sun’re.

6. O d’owuro sa ni, olufe mi.

A tun fere ri na ;nibiti

Ipinya ati ituka ko si.

Sun’re sun ‘re sun’re.

7. Tit’ ao fi pade niwaju ‘te Rre.

Nin aso igbunwa awon Tire.

Tit’ ao mo gege bi a ti mo wa.

Sun’re sun ‘re sun’re.

Amin.

9. Oore-Ofe (Benediction)

2. Calm is thy slumber as an infant’s sleep; But thou shalt wake no more to toil and weep; Thine is a perfect rest, secure and deep Good-night! Good-night! Good-night!

3. Until the shadows from this earth are cast; Until He gathers in His sheaves at last; Until the twilight gloom is over-past. Good-night! Good-night! Good-night!.

4. Until the Easter glory lights the skies; Until the dead in Jesus shall arise, And He shall come, but not in lowly guise Good-night! Good-night! Good-night!.

5. Until made beautiful by Love Divine, Thou in the likeness of thy Lord shalt shine

And He shall bring that golden crown of thine Good-night! Good-night! Good-night!.

6. Only “good-night,” beloved-not “farewell!” A little while, and all His saints shall dwell In hallowed union, indivisible Good-night! Good-night! Good-night!.

7. Until we meet again before His throne, Clothed in the spotless robe He gives His own, Until we know even as we are know Good-night! Good-night! Good-night!. Amen.

1. Orin Ibere (Opening Hymn)

ORIN 327 - L’OWURO OJO AJINDE

1. L’owuro ojo ajinde

T’ara t’okan yo pade

Ekun, kanu on irora

Yo dopin.

2. Nihin, won ko le sai pinya

Ki ara ba le simi

Ko si fi idake roro

Sun fonfon.

3. Fun ‘gba die ara are yi

La gbe sibi ‘simi re

Titi di imole oro

Ajinde.

4. Sugbon okan to ns’asaro

To si ngbadura kikan

Yo bu s’orin ayo lojo

Ajinde.

5. Ara at’okan yo dapo

Ipinya ko ni si mo

Won o ji ‘aworan Krist’ni ‘Telorun.

6. A! ewa na at’ayo na

Yo ti po to l’Ajinde!

Yo duro borun ataye

Ba fo lo.

7. L’oro ojo ajinde wa

‘Boji yo m’oku re wa

Baba, iya, omo , ara

Yo pade.

HYMN 327 - ON THE RESURRECTION MORNING

1. On the Resurrection morning

Soul and body meet again, No more sorrow, no more weeping, No more pain!.

2. Here awhile they must be parted, And the flesh its sabbath keep, Waiting in a holy stillness, Wrapt in sleep.

3. For a space the tired Body Lies with feet toward the dawn, Till there breaks the last and brighest Eastern morn.

4. But the soul in contemplation Utters earnest pray’r and strong, Bursting at the Resurrection into song.

5. Soul and body reunited Thenceforth nothing shall divide, Waking up in Christ’s own likeness, Satisfied.

6. Oh! the beauty, Oh! the gladness, Of that Resurrection day, Which shall not through endless ages Pass away!.

7. On that happy Easter morning

All the graves their dead restore, Father, sister, child and mother, Meet once more.

8. Si ‘dapo ti o dun bayi

Jesu ma sai ka wa ye

N’nu ‘ku ‘dajo, ka le ro m’a Gbelebu.

Amin.

8. To that brightest of all meetings

Bring us, Jesus Christ, at last, To Thy Cross, through death and judgement

Holding fast.

2. Adura (Prayer)

3. Eko Kika (Bible Reading)

4. Orin Adako (Special Rendition)

5. Iwaasu (Sermon)

6. Adura Lehin Iwaasu (Prayer after Sermon)

7. Adura fun Ebi Oloogbe (Prayer for the Family of the Deceased)

8.

9.

10.

11. Orin Ipari Isin (Closing Hymn)

ORIN 963 - JERUSALEMU T’ ORUN

1. Jerusalemu t’ orun

L’orin mi, ilu mi.

Ile mi bi mba ku.

Ekun ibukun mi,

HYMN 963 - JERUSALEM ON HIGH

1. Jerusalem on high

My song and city is,

My home whene’er I die, The centre of my bliss.

Amen.

Ifilo (Announcement) Idupe Ijade Oku (Thanksgiving) Oro Idupe (Vote of Thanks)

Ibi ayo

Nigbawo ni.

Un o r’oju Re. Olorun mi.

2. Nibe l’oba mi wa.

T’a da l’ebi l’aye ; Angeli nkorin fun.

Won si nteriba fun.

3. atriark igbani , ar’ ayo won nibe.

Awon woli , won now.

Omo Alade won.

4. Nibe ni mo le ri.

Awon Aposteli ; At’ awon akorin.

Ti nlu harpu wura.

5. Ni agbala wonni, Ni awon Martir wa.

Won wo aso ala.

Ogo bo ogbe won.

6. T’emi yi sa su mi, Tit’mo ngb’ ago Kedar’

Ko si r’yi loke, Nibe ni mo fe lo.

O happy place! When shall I be, My God,with Thee, to see Thy face!

2. There dwells my Lord, my King, Judged here unfit to live; There angels to Him sing, And lowly homage give.

3. The patriarchs of old There from their travels cease; The prophets there behold Their long’d-for Prince of Peace.

4. The Lamb’s apostles there I might with joy behold; The harpers I might hear Harping on harps of gold.

5. The bleeding martyrs, they Within those courts are found; All cloth’d in pure array, Their scars with glory crown’d.

6. Ah me! Ah me! That I In Kedar’s tents here stay: No place like this on high; Thither, Lord, guide my way.

Amin

Amen.
Oore-Ofe (Benediction)
Adura (Prayer)
13.
12.

Life & Career

Evangelist (Mrs.) Victoria Oyenike Adegoke

nee Oyewole was born on 22nd August 1950 into the Royal family of Aminu of Gbongan in Osun State. She started her elementary school in Olofi Memorial Primary School, Gbongan in the year 1956 and finished in 1962. She proceeded to Olu Orogbo High School (as a boarder), Ile-Ife in 1963-1965. After this, she proceeded to the school of Stenography, Ikire in 1965-1968 for three (3) years course in Commercial Training which she could not complete because of financial constraints. After this, she ventured into trading. She did this for some time before she decided to acquire the Fashion Designing Skill. With this certificate of fashion, she was granted to travel to the UK in 1991.

Mummy was a business tycoon and a contractor. She got several contracts with the Governments which she executed diligently and professionally. She was also at a point in time a supplier at the University Teaching Hospital (U.C.H), Ibadan. She stopped this when the family relocated to Lagos in 1988.

Upon relocation to Lagos, she focused on sales of clothes which she did on wholesales basis. She often travelled to Aba to get the clothes in a large variety. These she sold at the Answani Market and at her shop at Jakande Market, Isolo, Lagos -state.

Mummy was also a farmer. She was allocated 25 acres of land at Eruwa Farm Settlement by the Oyo State Government in 1987.

Call to Ministry

Evangelist (Mrs.) Victoria Oyekemi Adegoke started ministry tutelage (tulle) at CAC Oke And Ikon, Elbe Lagos, under the supervision of Late Pastor Otunla between 1990-1992. Between 1992 and 1995, she was directed by the Holy Spirit to CAC Headquarters Ikon, Sun State for another round of tutelage (tulle) under supervision of Pastor Fadipe. In 1993, she was sent to CAC (Oke Ayo) Apomu, in Osun State as an evangelist in training. This spanned for a year. She was shepherded by Pastor Olu Eyebiokun.

Evangelist (Mrs.) Victoria Oyekemi Adegoke later attended a special Christian Leadership Course headed by Pastor S.O. Oladele, in Ibadan. She started her career as a minister of God in Ibadan when the family relocated back to Ibadan in 1994 at CAC Oke Olorunkiiseti, Cajole, Ibadan, under Prophet M.O. Olowere till 2004.

After ten years of service with Baba M.O Oluwere, she was compelled by the Holy Spirit to go and plant a church at Akiriboto in Sun State. All this time, she was still under Baba Oluwere’s supervision.

In 2007, she was compelled by the Holy Spirit to resign from CAC Oke Olorunkiiseti Cajole, Ibadan to plant a church again. Thus, CAC Fountain of Mercy Oloruntedo, Orogbangbo in Oki Ibadan.

Evangelist (Mrs.) Victoria Oyekemi got married to her heartthrob in 1972. They became co-labourers in God’s vineyard and they are blessed with four godly biological children many spiritual children and many grandchildren.

Mother

Aquiderias enihit aut omnis sit qui dolorrum accus, vent aut reped maior accum erit moluptaerum ipsum et ea sus ant ut et lam, si quasi ide eritatus sunt, con nos mint fugitatur atias dendae lit officit pro qui di omnim faci nonsequatem. Ut hil min none conseque ped mod qui ut aut denis essin plis ex est, velit ex est, quia necture rsperferciae sinciis utem quodi que volupis es doluptur, ario di ut qui que et que non rerrum rest ra qui ratium as as a nonemque nis nos volorem aria velluptatur renda dia enditate volorion consequ iaerum - Tribute 1

Aquiderias enihit aut omnis sit qui dolorrum accus, vent aut reped maior accum erit moluptaerum ipsum et ea sus ant ut et lam, si quasi ide eritatus sunt, con nos mint fugitatur atias dendae lit officit pro qui di omnim faci nonsequatem. Ut hil min none conseque ped mod qui ut aut denis essin plis ex est, velit ex est, quia necture rsperferciae sinciis utem quodi que volupis es doluptur, ario di ut qui que et que non rerrum rest ra qui ratium as as a nonemque nis nos volorem aria velluptatur renda dia enditate volorion consequ iaerum - Tribute 1

Aquiderias enihit aut omnis sit qui dolorrum accus, vent aut reped maior accum erit moluptaerum ipsum et ea sus ant ut et lam, si quasi ide eritatus sunt, con nos mint fugitatur atias dendae lit officit pro qui di omnim faci nonsequatem. Ut hil min none conseque ped mod qui ut aut denis essin plis ex est, velit ex est, quia necture rsperferciae sinciis utem quodi que volupis es doluptur, ario di ut qui que et que non rerrum rest ra qui ratium as as a nonemque nis nos volorem aria velluptatur renda dia enditate volorion consequ iaerum - Tribute 1

Aquiderias enihit aut omnis sit qui dolorrum accus, vent aut reped maior accum erit moluptaerum ipsum et ea sus ant ut et lam, si quasi ide eritatus sunt, con nos mint fugitatur atias dendae lit officit pro qui di omnim faci nonsequatem. Ut hil min none conseque ped mod qui ut aut denis essin plis ex est, velit ex est, quia necture rsperferciae sinciis utem quodi que volupis es doluptur, ario di ut qui que et que non rerrum rest ra qui ratium as as a nonemque nis nos volorem aria velluptatur renda dia enditate volorion consequ iaerum - Tribute 1

Grand Mother

Ever since you left, things has not been the same. You did not wait to see Iyioluwa. We will have to tell her about you and how loving you were. I miss you Sweet Grandma. You are the only one who always call me Pekutu. Rest well Grandma. - Adegoke Mayokun

Dear Grandma,

Grandma, you were a wonderful and very loving grandma. You loved me specially, and I love you too. So sad that there will not be anyone to call me Orobo. I love you Grandma.Adegoke Ireoluwa

Grandma I miss you. You were the best grandma to I and my sisters. I love you grandma because you love me. MAY YOUR SOUL REST IN PEACE - Adegoke Momoreoluwa

I will really miss you. Rest In Peace - Oreoluwa Adegoke

I miss you. I still can’t believe you are not here with me, I won’t hear you call my name again, I miss. your stories. May your soul rest in perfect peace. I will never forget you. I love you.Oluwajuwon Adegoke

Grandma you always care for me. You correct me. Any child who comes to you will never be the same. I can’t believe you went so early but I cannot blame God. Everybody has their time. MAY YOUR SOUL REST IN PEACE - Iyanuoluwa Adegoke

Grandma I love you so much and I will miss you when we see together in heaven. May your soul Rest In Peace. - John Adegoke

We all love you and we will miss you. Rest In Peace - Moyinoluwa Adegoke

I really miss you. I love you. Keep on resting - Moyo Adegoke

Turn static files into dynamic content formats.

Create a flipbook
Issuu converts static files into: digital portfolios, online yearbooks, online catalogs, digital photo albums and more. Sign up and create your flipbook.