1. Praise & Worship
2. Opening Hymn
ORIN 329 - JESU YE TITI AYE
1. Jesu ye titi aye, Eru iku ko ba mi mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko nâipa mo Aleluya.
2. Jesu ye, latâoni lo, Iku je ona s iye; Eyi yâo je âtunu wa âGbatâakoko iku ba de Aleluya.
3. Jesu ye; fun wa lo ku, Nje Tire, ni a o ma se; A o fâokan funfunsin, A o fâogo fâOlugbala Aleluya.
4.Jesu ye; eyi daju, Iku atâipa okunkun
Ki yo le ya ni kuro
Ninu ife nla ti Jesu Aleluya.
5.Jesu ye; gbogbo âjoba Lâorun, li aye, di Tire; E je ki a ma tele, Ki a le jona pelu Re Aleluya.
Amin.
HYMN 329 - JESUS LIVES!
1. Jesus lives! thy terrors now Can, O death, no more appal us, Jesus live! by this we know Thou, O grave, canst not enthral us Hallelujah!
2. Jesus lives! henceforth is death
Entrance-gate of life immortal; This hall calm our trembling breath
When we pass its gloomy portal, Hallelujah!
3. Jesus lives! for us He died; Hence may we, to Jesus living
Pure in heart and act abide, Praise to Him and glory giving, Hallelujah!
4. Jesus live! our hearts know well
Nought from us His love shall sever, Life, nor death, nor powârs of hell, Part us now from Christ for ever, Hallelujah!
5. Jesus lives! to Him throne
High oâer heavân and earth is given; We may go where He is gone, Live and reign with Him in heaven. Hallelujah!
3. Opening Prayer
4. Hymn
ORIN 975 - AO PADE LâETI ODO
1. Ao pade lâeti odo
Tâese angeli ti te.
Ttâo mo gara bi Kristali
Lâeba ite Olorun.
A o pade lâeti odo didan
Odo didan , odo didan na.
Ttâo nsan lâeba ite ni.
2. Lâeti bebe odo na yi
Ao râoju Olugbala;
Emi wa ki o si pinya mo; Yio korin ogo Re.
3. Nje lâeba odo tutu na, Ao râoju Olugbala;
Emi wa ki yio pinya mo
Yio korin ogo Re.
4. Kâa to de odo didan na, A o sâeru wa kale.
Jesu yâo gba eru ese;
Awon ti O de lâade
5. A fe de odo didan na, âRin ajo wa fere pin; Okan wa kun fâorin
Ayo atâ Alafia. Amin.
HYMN 975 - SHALL WE GATHER AT THE RIVER
1. Shall we gather at the river
Where bright angel feet have trod; With its crystal tide for ever Flowing by the throne of God!
Yes, weâll gather at the river, The beautiful, beautiful river; Gather with the saints at the river. That flows by the throne of God.
2. On the margin of the river, Guided by our Shepherd King, We will walk and worship ever, His dear footsteps following.
3. There beside the tranquil river, Mirror of the saviourâs face, Happy hearts, no more to sew, Sing of glory and of grace.
4. But before we gain the river, Lay we every burden down; Jesus, here from sin deliver, Those whom there Thy grace will crown.
5. Soon weâll reach the crystal river; Soon our pilgrimage will cease; Soon our golden harpstrings quiver, With the melody of peace. Amen.
5. 1st Bible Reading - 1 Corinthians 15:50-58
6. Hymn
ORIN 967 - A NSORO ILE âBUKUN NI
1. A nsoro ile âbukun ni, Ile didan atâ ile ewa.
âGbagbogbo lâa nso tâogo re.
Yâo ti dun to lati de be.
2. A nsoro ita wura Re. Oso odi re ti ko lâegbe, âFaji re ko se fâenu so Yâo ti dun to lati de be,
3. A nso p; ese ko si nibe. Ko sâaniyan atâ ibanuje, elu âdanwolâode , ninu; Tâo ti dun lati de be,
4. A nsoro orin iyin re. Ti a kole fâorin aye we.
Bâo ti wu kâorin wa dun to.
Yâo ti dun to lati de be,
5. A nsoro isin ife re.
Ti agbada tâawon mimo nwo.
Ijo akobi ti oke;
Yâo ti dun to lati de be.
6. Jo Oluwa lâonakona, Sa emi wa ye fun orun.
Laipe awa na yio mo, Bâ o ti dun to lati de be, Amin
HYMN 967 - WE SPEAK OF THE REALMS OF THE BLEST
1. We speak of the realms of the Blest, Of that country so bright and so fair, And oft are its glories confessâd; But what must it be to be there?
2. We speak of its pathway of gold, Of its walls deckâd with Jewels most rare Its wonders and pleasures untold But what must it be to be there?
3. We speak of its freedom from sin, From sorrow, temptation, and care, From trials without and within? But what must it be to be there?
4. We speak of its anthems of praise, With which we can never compare The sweetest on earth we can raise; But what must it be to be there?
5. We speak of its service of love, Of the robes which the glorified wear, The Church of the First-born above, But what must it be to be there?
6. Do Thou, Lord, âmidst pleasure of woe, Still for Heavân our spirits prepare; And shortly we also shall know And feel what it is to be there. Amen.
7. 2nd Bible
Reading - John 14:1-6
8. Hymn
ORIN 953 - IGBATI IPE OLUWA BA DUN
1. IGbati ipe Oluwa ba dun, tâaye yâo si fo lo, Ti imole ojo titun yâo si de; Nigbati awon omo igbala ba pejo lâoke,
Tâa ba si pâoruko ;âohun, un o wa nâbe
âGbatâ a ba pâoruko lâohun, âGbatâ a ba pâoruko lâohun, âGbatâ a ba pâoruko lâohun, Nipa ore-ofe nikan, un o wa nâbe,
2. lâoro ojo na tâawon oku nânu Kristi yâo jinde, Ti won yâo si pin nânu ogo ajinde; âGbati awon ayanfe yâo pejo si ode orun,
Tâa ba si pâoruko ;âohun, un o wa nâbe
3. Jeki a fi gbogbo akoko wa sise fâOluwa
Jeki a royin ife iyanu Re; Nigbati a ba si pari ire ije wa lâaye, Tâa ba si pâoruko lâohun, un o wa nâbe.
Amin.
HYMN 953 - WHEN THE TRUMPET OF THE LORD SHALL SOUND
1. When the trumpet of the Lord shall sound, and time shall be no more, And the morning, breaks, eternal, bright and fair;
When the saved of earth shall gather over on the other shore, And the roll is called up yonder, Iâll be there.
When the roll is called up yonder, When the roll is called up yonder, When the roll is called up yonder, When the roll is called up yonder, Iâll be there.
2. On that bright and cloudless morning when the dead in Christ shall rise, And the glory of His resurrection share; When His chosen ones shall gather to their home beyond the skies, And the roll is called up yonder, Iâll be there.
3. Let us labour for the Master from the dawn till setting sun,
Let us talk of all His wondrous love and care; Then when all of life is over, and our work on earth is done, And the roll is called up youder, Iâll be there. Amen.
10. Hymn
ORIN 333 - IJA DâOPIN, OGUN SI TAN
1. Ija dâopin, ogun si tan; Olugbala jagun molu, Orin ayo la o ma ko Alleluya.
2. Gbogbo ipa nâiku ti lo, Sugbon Kristi fâogun re ka: Aye! e ho iho ayoAlleluya
3. Ojo meta na ti koja, O jinde kuro ninâoku, E fâogo fun Oluwa waAlleluya.
4. O dâewon orun apadi, O silekun orun sile, E korin iyin âsegun ReAlleluya.
5. Jesu nipa iya tâo je, Gba wa lowo oro iku, Kâa le ye, kâa si ma yin O-Alleluya.
Amin
HYMN 333 - THE STRIFE IS OâER, THE BATTLE DONE
1. The strife is oâer, the battle done; The victory of life is won; The song of triumph has begun,Alleluia!
2. The powârs of death have done their worst
But Christ their legions hath dispersed; Let shouts of holy joy outburst,Alleluia!
3. The three sad days have quickly speed; He rises glorious from the dead; All glory to or risen Head! Alleluia!
4. He brake the age-bound chains of hell; The bars from heavâns high portals fell; Let hymns of praise His triumph tell: Alleluia!
5. Lord, by the stripes which wounded Thee, From deathâs dread sting Thy servants free, That we may live, and sing to Thee Alleluia! Amen.
11.
4th Bible Reading - 1
Thessalonians 4:13-18
12. Hymn
ORIN 963 - JERUSALEMU Tâ ORUN HYMN 963 - JERUSALEM ON HIGH
1. Jerusalemu tâ orun
Lâorin mi, ilu mi.
Ile mi bi mba ku.
Ekun ibukun mi,
Ibi ayo
Nigbawo ni.
Un o râoju Re.
Olorun mi.
2. Nibe lâoba mi wa.
Tâa da lâebi lâaye ;
Angeli nkorin fun.
Won si nteriba fun.
3. atriark igbani , arâ ayo won nibe.
Awon woli , won now.
Omo Alade won.
4. Nibe ni mo le ri.
Awon Aposteli ; Atâ awon akorin.
Ti nlu harpu wura.
5. Ni agbala wonni, Ni awon Martir wa.
Won wo aso ala.
Ogo bo ogbe won.
6. Tâemi yi sa su mi, Titâmo ngbâ ago Kedarâ
Ko si râyi loke, Nibe ni mo fe lo. Amin
1. Jerusalem on high My song and city is, My home wheneâer I die, The centre of my bliss.
O happy place! When shall I be, My God,with Thee, to see Thy face!
2. There dwells my Lord, my King, Judged here unfit to live; There angels to Him sing, And lowly homage give.
3. The patriarchs of old There from their travels cease; The prophets there behold Their longâd-for Prince of Peace.
4. The Lambâs apostles there I might with joy behold; The harpers I might hear Harping on harps of gold.
5. The bleeding martyrs, they Within those courts are found; All clothâd in pure array, Their scars with glory crownâd.
6. Ah me! Ah me! That I In Kedarâs tents here stay: No place like this on high; Thither, Lord, guide my way.
ORIN 935 - MA SUN, OLUFE; KâO SIMA SIMI
1. Ma sun , olufe ; kâo sima simi
Gbâ ori re le aya Olugbala
A fe o sugbon Jesu fe o ju.
Sun âre sun âre sun re.
2. Orun re dun bi orun omode, Iwo ki yo si ji si ekun mo.
Isimi tâo daju nâismi re.
Sun âre sun âre sun âre.
3. Titâ ao ka okunkun aye kuro
Titâ ao fi ko ikore âwole
Titâ oye yio fi la,
Sun âre sun âre sun âre
4. Titâ orun ajinde yâo fi yo
Tâawon oku nânu Jesu yâo dide
On yâo si wa ninu olanla Re.
Sun âre sun âre sunâre.
HYMN 935 - SLEEP ON, BELOVED, SLEEP AND TAKE THY REST
1. Sleep on, beloved, sleep and take thy rest; Lay down thy head upon thy Saviourâs breast; We love thee well; but Jesus loves thee best.
Good-night! Good-night! Good-night!.
2. Calm is thy slumber as an infantâs sleep; But thou shalt wake no more to toil and weep; Thine is a perfect rest, secure and deep
Good-night! Good-night! Good-night!.
3. Until the shadows from this earth are cast; Until He gathers in His sheaves at last; Until the twilight gloom is over-past.
Good-night! Good-night! Good-night!.
4. Until the Easter glory lights the skies; Until the dead in Jesus shall arise, And He shall come, but not in lowly guise
Good-night! Good-night! Good-night!.
5. Titâ ewa orun yâo je tire
Ti iwo o ma ran ninu ogo
Oluwa yâo de o lâade wura.
Sunâre sunâre sunâre.
6. O dâowuro sa ni, olufe mi.
A tun fere ri na ;nibiti
Ipinya ati ituka ko si.
Sunâre sun âre sunâre.
7. Titâ ao fi pade niwaju âte Rre.
Nin aso igbunwa awon Tire.
Titâ ao mo gege bi a ti mo wa.
Sunâre sun âre sunâre.
21. Benediction
Amin.
5. Until made beautiful by Love Divine, Thou in the likeness of thy Lord shalt shine And He shall bring that golden crown of thine Good-night! Good-night! Good-night!.
6. Only âgood-night,â beloved-not âfarewell!â A little while, and all His saints shall dwell In hallowed union, indivisible Good-night! Good-night! Good-night!.
7. Until we meet again before His throne, Clothed in the spotless robe He gives His own, Until we know even as we are know Good-night! Good-night! Good-night!.
Amen.