Sekariah
ORI1
1LIoṣùkẹjọ,liọdunkejiDariusi,liọrọOluwatọSekariah, ọmọBerekiah,ọmọIddowoliwá,wipe, 2OLUWAtibínúsíàwọnbabańláyín
3Nitorinawifunwọnpe,BayiliOluwaawọnọmọ-ogun wi;Ẹyipadasimi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,emiosi yipadasinyin,liOluwaawọnọmọ-ogunwi
4.Ẹmáṣedabiawọnbabanyin,tiawọnwoliiṣãjukigbesi wipe,BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Ẹyipadanisisiyi kuroninuọnabuburunyin,atikuroninuiṣebuburunyin: ṣugbọnnwọnkògbọ,bẹninwọnkògbọtiemi,liOluwawi. 5Awọnbabanyin,niboninwọnwà?atiawọnwoli,nwọn hawàlãyelailai?
6Ṣugbọnọrọmiatiilanami,timopalaṣẹfunawọniranṣẹ mi,awọnwoli,nwọnkòhadìawọnbabanyinmu?nwọnsi padanwọnsiwipe,GẹgẹbiOLUWAawọnọmọ-oguntirò latiṣesiwa,gẹgẹbiọnawa,atigẹgẹbiiṣewa,bẹlioṣesi wa
7Níọjọkẹrinlelogunoṣùkọkanla,tííṣeoṣùSebati,ní ọdúnkejìDáríúsì,niọrọOlúwatọwòlíìSekaráyàọmọ BerekáyàọmọÍdòwòlíìwápé:
8Mosirilioru,sikiyesii,ọkunrinkangunẹṣinpupakan, osidurolãrinawọnigimirtilitiowàniisalẹ;lẹhinrẹni awọnẹṣinpupa,abilà,atifunfunwà
9Nigbananimowipe,Oluwami,kiniwọnyi?Angeliti mbamisọrọsiwifunmipe,Emiofiohuntiawọnwọnyi iṣehànọ
10Ọkunrinnatiodurolãrinawọnigimirtilinadahùnosi wipe,WọnyiliawọntiOLUWAránlatimarìnsodesodò liaiye
. 12AngeliOLUWAnasidahùnosiwipe,Oluwaawọn ọmọ-ogun,yiotipẹtotiiwọkìyioṣãnufunJerusalemuati funawọniluJuda,tiiwọtibinusiliãdọrinọdunwọnyi?
13OLUWAsifiọrọrereatiọrọitunudaangẹlinatimba misọrọlohùn
14Angelitimbamisọrọsiwifunmipe,Iwọkigbe,wipe, BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Mojowúfun JerusalemuatifunSionipẹluowúnla
. 16NitorinabayiliOluwawi;EmipadasiJerusalemupẹlu ãnu:aokọilemisinurẹ,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,ao sitaokùnkansoriJerusalemu.
17Kigbesibẹ,wipe,BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi; Awọniluminipaalafiayootuntankaakiri;Oluwayiosi tuntuSionininu,yiositunyanJerusalemu.
18Nigbananimogbeojumisoke,mosiri,sikiyesii,iwo mẹrin
19Mosiwifunangelitiombamisọrọpe,Kiniwọnyi?O sidamilohùnpe,WọnyiliawọniwotiotitúJuda,Israeli, atiJerusalemuká
20OLUWAsifiawọngbẹnagbẹnamẹrinhànmi.
21Nigbananimowipe,Kiliawọnwọnyiwálatiṣe?Osi wipe,WọnyiniiwotiotitúJudaka,tobẹtiẹnikankògbe orirẹsoke:ṣugbọnawọnwọnyiwálatidẹrùbawọn,latilé iwoawọnKeferijade,tiogbéiwowọnsokesoriilẹJuda latitúuká
ORI2
1MOsitungbeojumisoke,mosiwò,sikiyesii,ọkunrin kantiotiokùnìwọnliọwọrẹ
2Nigbananimowipe,Niboniiwọnlọ?Osiwifunmipe, LatiwọnJerusalemu,latiwòbawoniibúrẹ,atibawoni gigùnrẹṣe
3Sikiyesii,angẹlitimbamisọrọjadelọ,angẹlimiransi jadelọipaderẹ;
4Osiwifunupe,Sá,sọfunọdọmọkunrinyipe, Jerusalemuliaomagbebiilutikòniodinitoriọpọlọpọ eniaatiẹran-ọsinninurẹ.
5Nitoripeemi,liOluwawi,emiojẹodiináfunuyika, emiosijẹogolãrinrẹ
6Ho,ho,jadewá,kiosisákuroniilẹariwa,liOluwawi: nitoriemitinànyinkakiribiafẹfẹmẹrinọrun,liOluwawi 7Gbàararẹlọwọ,ìwọSioni,tíońgbépẹluọmọbinrin Babiloni.
8NitoribayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Lẹyìnògo,ó ránmisíàwọnorílẹ-èdètíwọnkóyínníìjẹ:nítoríẹnitíó báfọwọkànyín,ófọwọkanpópóojúrẹ.
9Nitorikiyesii,emiomìọwọmilewọn,nwọnosidi ikogunfunawọniranṣẹwọn:ẹnyinosimọpeOluwaawọn ọmọ-ogunlioránmi.
10Kọrin,siyọ,iwọọmọbinrinSioni:nitori,wòo,emi mbọ,emiosimagbeãrinrẹ,liOluwawi
11Ọpọlọpọorilẹ-èdeniyiosidapọmọOluwaliọjọna, nwọnosijẹeniami:emiosimagbeãrinrẹ,iwọosimọ peOluwaawọnọmọ-ogunlioránmisiọ
12OluwayiosijogunJudaipínrẹniilẹmimọ,yiositun yanJerusalemu
13Ẹdákẹ,gbogboeniyan,níwájúOLUWA,nítoríótijí dìdekúròníibùgbémímọrẹ
ORI3
1OsifiJoṣuaolorialufahànmi,oduroniwajuangẹli Oluwa,Satanisiduroliọwọọtúnrẹlatikojurẹ.
2OLUWAsiwifunSatanipe,Oluwabaọwi,iwọSatani; aniOluwatiotiyànJerusalemu,baọwi:eyihahahafà yọkuroninuiná?
3AsiwọJoṣualiaṣọẽri,osiduroniwajuangẹlina
4Osidahùnosisọfunawọntioduroniwajurẹpe,Ẹbọ aṣọẽrinìkurolararẹ.Onsiwipe,Kiyesii,emitimuẹṣẹrẹ kọjalọdọrẹ,emiosifiàparọaṣọwọọ
5Emisiwipe,Kinwọnkiofifiladaradarakanleeliori Bẹninwọnfifiladidanléeliori,nwọnsifiaṣọwọọ. AngeliOLUWAnasidurotìi
6AngeliOLUWAnasisọfunJoṣuape, 7BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Biiwọobarìnliọna mi,atibiiwọobapaaṣẹmimọ,nigbananiiwọoṣeidajọ ilemipẹlu,iwọosipaàgbalamimọpẹlu,emiosifunọli àyelatimarìnlãrinawọntioduronibẹ.
8Gbọnisisiyi,iwọJoṣuaolorialufa,iwọ,atiawọnẹgbẹrẹ tiojokoniwajurẹ:nitoritiẹnuyàwọnlienia:sawòo,emi omuiranṣẹmijade,Ẹka.
9Nitorikiyesii,okutatimotigbekalẹniwajuJoṣua;sori okutakanliojumejeyiowà:kiyesii,emiofinfinfinrẹ,li Oluwaawọnọmọ-ogunwi,emiosimuẹṣẹilẹnakuroni ijọkan
10Liọjọna,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,olukulukunyin opèaladugborẹlabẹajaraatilabẹigiọpọtọ.
1Áńgẹlìtíóńbámisọrọsìtúnpadàwá,ósìjími,bí ọkùnrintíajílójúoorun.
2Osiwifunmipe,Kiniiwọri?Mosiwipe,Motiwò,si kiyesii,ọpá-fitilakangbogbotiwura,pẹlukanàwokòtò lorirẹ,atimejefitilarẹlorirẹ,atipaimejefunawọnfìtílà meje,tiowàlorirẹ.
3Atiigiolifimejiliẹbarẹ,ọkanliapaọtúnawokòtona, atiekejiliapaòsirẹ
4Mosidahùnmosiwifunangelitimbamisọrọpe,Kini wọnyi,oluwami?
5Nigbanaliangelitimbamisọrọdahùnosiwifunmipe, Iwọkòmọohuntiawọnwọnyijasi?Emisiwipe,Bẹkọ, oluwami
6Nigbanaliodahùnosisọfunmipe,EyiliọrọOluwasi Serubbabeli,wipe,Kiiṣenipaagbara,tabinipaagbara, bikoṣenipaẹmimi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi
7Taniiwọ,okenla?niwajuSerubbabeliiwọodipẹtẹlẹ:on osifiariwomúokutaorirẹjade,tinkigbepe,Ore-ọfẹ, ore-ọfẹsii
8PẹlupẹluọrọOluwatọmiwá,wipe, 9ỌwọSerubbabeliliotifiipilẹileyilelẹ;ọwọrẹyóòsì parírẹ;iwọosimọpeOLUWAawọnọmọ-ogunliorán misinyin.
10Nitoripetaliogànọjọohunkekere?nitoritinwọnoyọ, nwọnosiriòṣuwọnliọwọSerubbabelipẹluawọnmejeje; ojúOLUWAniwọn,tíwọnńsálọsíwásẹyìnnígbogbo ayé
11Nigbananimodahùn,mosiwifunupe,Kiniawọnigi olifimejejiyiliapaọtúnọpá-fitilana,atiliapaòsirẹ?
12Mositundahùnmosiwifunupe,Kiliawọnẹkaolifi mejejiwọnyi,tiodàororowurànajadelatiinupaṣanwurà mejejinì?
13Osidamilohùnosiwipe,Iwọkòmọohuntiawọn wọnyijasi?Emisiwipe,Bẹkọ,oluwami
14Nigbanaliowipe,Awọnwọnyiliawọnẹni-àmi-ororo mejeji,tiodurotìOluwagbogboaiye
ORI5
1MOsiyipada,mosigbeojumisoke,mosiwò,sikiyesi i,iwe-kikátinfò.
2Osiwifunmipe,Kiniiwọri?Mosidahùnpe,Mori iwe-kikatinfò;gigùnrẹjẹogúnigbọnwọ,atiibúrẹ igbọnwọmẹwa.
3Nigbanaliowifunmipe,Eyiliegúntiojadelori gbogboaiye:nitorigbogboẹnitiojaleliaokekurobiiha ìhingẹgẹbirẹ;atiolukulukuẹnitioburaliaokekuro gẹgẹbiihaọhún
4Emiomuujade,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,yiosiwọ inuileolèlọ,atisinuileẹnitiofiorukọmiburaeke:yiosi durolãrinilerẹ,yiosirunupẹluigiatiokutarẹ
5Nigbanaliangelitimbamisọrọjadelọ,osiwifunmipe, Gbeojurẹsokenisisiyi,kiosiwòkinieyitiojadelọ
6Mosiwipe,Kilieyi?Onsiwipe,Eyiniefatiojadelọ Ósìtúnsọpé,“Èyíniìríwọnjákèjádòayé.
7Sikiyesii,agbetalentiojékansoke:eyisiniobinrin kantiojokoliãrinòṣuwọnefa
8Osiwipe,Eyiliìwa-buburu.Ósìsọọsíàárínòṣùwọn eéfànáà;ósìgbéòjéwúwoléenurÆ
9Nigbananimogbeojumisoke,mosiwò,sikiyesii, obinrinmejijadewá,afẹfẹsiwàninuiyẹwọn;nitoriti nwọnniiyẹbiiyẹàkọ:nwọnsigbéefanasokelarinaiye atiọrun.
10Nigbananimowifunangelitiombamisọrọpe,Nibo liawọnwọnyigbéefana?
11Osiwifunmipe,LatikọilefununiilẹṢinari:aosifi idirẹmulẹ,aosifiipilẹrẹkalẹnibẹ.
ORI6
1MOsiyipada,mosigbeojumisoke,mosiwò,sikiyesi i,kẹkẹmẹrinjadelatiagbedemejiòkemeji;àwọnòkèńlá sìjẹòkèidẹ
2Awọnẹṣinpupawàninukẹkẹekini;atininukẹkẹkeji awọnẹṣindudu;
3Atiawọnẹṣinfunfunnikẹkẹkẹta;atininukẹkẹkẹrin,a figirigiriatiawọnẹṣinonijagidijagan
4Nigbananimodahùnmosiwifunangelitiombami sọrọpe,Kiniwọnyi,oluwami?
5Angẹlinasidahùnosiwifunmipe,Wọnyiliawọnẹmi mẹrinọrun,tiojadekuroniiduroniwajuOluwagbogbo aiye
6Awọnẹṣindudutimbẹninurẹjadelọsiilẹariwa;ati awọnfunfunjadelọlẹhinwọn;+àwọntíafigìlìsìjádelọ síìhàgúúsù
7Awọnokunsijadelọ,nwọnsinwáọnaatilọ,kinwọnki olerìnsihinsọhunliaiye:osiwipe,Ẹjadekuronihin,ẹ rìnsohinsọhunliaiyeBẹẹniwọnrìnsíwásẹyìnníayé
8Nigbanaliokigbesimi,osibamisọrọpe,Kiyesii, awọnwọnyitiolọsiìhaariwatipaẹmimiliẹnuniilẹ ariwa
9ỌrọOluwasitọmiwá,wipe, 10Muninuawọntiigbekun,anitiHeldai,tiTobijah,ati ninuJedaiah,tiotiBabeliwá,kiiwọkiosiwáliọjọna gan,kiosilọsiileJosiah,ọmọSefaniah;
11Lẹyìnnáà,múfàdákààtiwúrà,kíosìṣeadé,kíosìfi wọnléJóṣúàọmọJósédékìolóríàlùfáàlọwọ;
12Kiosisọfunupe,BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi, wipe,WòọkunrinnatiijẹẸka;yiosidagbalatiipòrẹ,yio sikọtẹmpiliOluwa
13AnionniyiokọtempiliOluwa;onosiruogo,yiosi joko,yiosijọbaloriitẹrẹ;onosijẹalufaloriitẹrẹ:ìmọ alafiayiosiwàlãrinawọnmejeji
14AdénáàyóòsìjẹtiHélémù,àtifúnTóbíjà,àtifún Jédáyà,àtifúnHénìọmọSefanáyà,fúnìrántínítẹńpìlì Olúwa
15Àwọntíójìnnàréréyóòwá,wọnyóòsìkọiléOlúwa, ẹyinyóòsìmọpéOlúwaàwọnọmọ-ogunnióránmisíyín Èyíyóòsìṣẹlẹ,bíẹyinyóòbáfitarataragbọrànsíOlúwa Ọlọrunyíngbọ
ORI7
1OSIṣeliọdunkẹrinDariusiọba,liọrọOluwatọ Sekariahwáliọjọkẹrinoṣukẹsan,aniniKisleu; 2NigbatinwọnsiranṣẹsiileỌlọrunṢereseriati Regemmeleki,atiawọnọmọkunrinwọn,latigbadura niwajuOluwa
3AtilatisọfunawọnalufatiowàniileOluwaawọnọmọogun,atifunawọnwoli,wipe,Kiemikiosọkunlioṣù
karun,kiemikioyaaramisọtọ,gẹgẹbimotiṣeliọdun pipọbayi?
4NigbanaliọrọOluwaawọnọmọ-oguntọmiwá,wipe;
5Sọfungbogboawọneniailẹna,atifunawọnalufape, Nigbatiẹnyingbààwẹ,tiẹnyinsiṣọfọlioṣùkarunatikeje, aniãdọrinọdunna,ẹnyinhagbàwẹfunmirara,anisiemi bi?
6Nigbatiẹnyinsijẹ,atinigbatiẹnyinmu,funaranyinkò hajẹ,tiẹnyinsimufunaranyin?
7ẸnyinkòhagbọọrọtiOluwatikigbelatiọwọawọnwoli iṣãju,nigbatiangbeJerusalemu,atininualafia,atiawọn ilurẹtioyiikakiri,nigbatiawọneniangbégusuatipẹtẹlẹ?
8ỌrọOluwasitọSekariahwá,wipe,
9BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwipe,Ṣeidajọotitọ,kio siṣeãnuatiãnu,olukulukusiarakunrinrẹ
10.Másiṣeniopólara,tabialainibaba,atialejò,tabi talakà;ẹmásiṣejẹkiẹnikẹnininunyinroibisiarakunrin rẹliọkànnyin
11Ṣugbọnnwọnkọlatigbọ,nwọnsifàejikakuro,nwọnsi dietíwọn,kinwọnkiomábagbọ
12Nitõtọ,nwọnṣeọkànwọnbiokutaadamanti,kinwọn kiomábagbọofin,atiọrọtiOluwaawọnọmọ-oguntifi ẹmirẹránnipaawọnwoliiṣãju:nitorinaibinunladelati ọdọOluwaawọnọmọ-ogun
13Nitorinaosiṣe,nigbatiokigbe,tinwọnkòsifẹgbọ; bẹninwọnkigbe,emikòsifẹgbọ,liOluwaawọnọmọogunwi
14Ṣugbọnmotúwọnkápẹluìjìlílesígbogboorílẹ-èdètí wọnkòmọBẹẹniilẹnáàtidiahorolẹyìnwọn,tíẹnikẹni kòfikọjá,bẹẹnikòsípada:nítoríwọnsọilẹdídùnnáàdi ahoro.
ORI8
1ỌRỌOluwaawọnọmọ-ogunsituntọmiwá,wipe, 2BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Owúńláǹlànimofi jowúfúnSíónì,mosìfiìbínúńláǹlàjowúfúnun.
3BayiliOluwawi;MotipadasiSioni,emiosimagbe ãrinJerusalemu:Jerusalemuliaosimapèniiluotitọ;àti òkèOlúwaàwọnọmọ-ogunòkèmímọ.
4BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Awọnarugboọkunrin atiawọnarugboobinrinyiomagbeniitaJerusalemu,ati olukulukupẹluọpárẹliọwọrẹfunogbó.
5Ìgboroilunayiosikúnfunọmọkunrinatiọmọbinrinti nṣereniitarẹ
6BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Bíóbájẹàgbàyanu lójúìyókùàwọnènìyànyìíníọjọwọnyí,yóòhajẹìyanuní ojúmipẹlúbí?liOluwaawọnọmọ-ogunwi.
7BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Kiyesii,emiogba awọneniamilàkuroniilẹila-õrun,atikuroniilẹiwọõrun;
8Emiosimuwọnwá,nwọnosimagbeãrinJerusalemu: nwọnosijẹeniami,emiosijẹỌlọrunwọnliotitọatili ododo
9BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Ẹjẹkíọwọyínle, ẹyintíẹńgbọọrọwọnyíníọjọwọnyílátiẹnuàwọnwòlíì, níọjọtíafiìpìlẹiléOlúwaàwọnọmọ-ogunlélẹ,kíalèkọ tẹḿpìlì
10Nítoríṣáájuọjọwọnyíkòsíọyàènìyàn,bẹẹnikòsíọyà fúnẹranko;bẹnikòsialafiafunẹnitiojadetabitinwọle nitoriipọnjuna:nitoritimofiolukulukueniadojukọ ẹnikejirẹ
11“Ṣùgbọnnísinsinyìí,èmikìyóòṣesíìyókùàwọn ènìyànyìígẹgẹbítiìgbààtijọ,”niOlúwaàwọnọmọ-ogun wí
12Nitoriirugbinnayiodara;àjàràyóòsoèsorẹ,ilẹyóòsì soèsorẹ,àwọnọrunyóòsìmúìrìwọnjáde;èmiyóòsìmú kíìyókùàwọnènìyànyìígbàgbogbonǹkanwọnyí
13Yiosiṣe,biẹnyintijẹegúnlãrinawọnkeferi,ẹnyinile Juda,atiileIsraeli;bẹliemiosigbànyin,ẹnyinosijẹ ibukún:ẹmáṣebẹru,ṣugbọnjẹkiọwọnyinkiole
14NitoribayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Gẹgẹbimoti ròlatijẹnyinniya,nigbatiawọnbabanyinmumibinu,li Oluwaawọnọmọ-ogunwi,tiemikòsironupiwada
15.Bẹliemisitunròliọjọwọnyilatiṣererefun JerusalemuatifunileJuda:ẹmáṣebẹru
16Wọnyiliohuntiẹnyinoṣe;Kiolukulukunyinsọotitọ funẹnikejirẹ;ṣeidajọotitọatialafianiiboderẹ.
17Ẹmásiṣejẹkiẹnikẹnininunyinroibiliọkànnyinsi ẹnikejirẹ;másiṣefẹiburaeke:nitorigbogbonkanwọnyi liemikorira,liOluwawi.
18ỌrọOluwaawọnọmọ-ogunsitọmiwá,wipe
19BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Ààwẹoṣùkẹrin, ààwẹkarùn-ún,ààwẹkeje,àtitiìkẹwàá,yóòjẹfúniléJúdà ayọàtiìdùnnú,àtiàsèìdùnnú;nitorinafẹotitọatialafia
20BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Yiositunṣe,awọn eniayiowá,atiawọnolugbeilupipọ;
21Awọnarailukanyiosilọsiekeji,wipe,Ẹjẹkiayara lọlatigbaduraniwajuOluwa,atilatiwáOluwaawọnọmọogun:emiosilọpẹlu.
22Nitõtọ,ọpọlọpọeniaatiawọnorilẹ-èdealagbaraniyio wálatiwáOluwaawọnọmọ-ogunniJerusalemu,atilati gbaduraniwajuOluwa.
23BayiliOluwaawọnọmọ-ogunwi;Níọjọwọn-ọn-nì, ènìyànmẹwàáyóòdìímúnínúgbogboèdèàwọnorílẹ-èdè, àníyóòsìdiẹwùtíójẹJúùmú,wípé,‘Àwayóòbáọlọ, nítoríàwatigbọpéỌlọrunwàpẹlúrẹ
ORI9
1ỌRỌỌRỌOluwaniilẹHadraki,Damaskuniyiosijẹ isimirẹ:nigbatiojuenia,bitigbogboẹyaIsraeli,yiombẹ siOluwa
2AtiHamatipẹluniyioṣeàgbegberẹ;Tire,atiSidoni,bi otilẹjẹpeogbọngidigidi.
3Tiresikọararẹodiagbara,osikófadakajọbierupẹ,ati wuràdaradarabiẹrẹita
4Kiyesii,Oluwayiotìajade,yiosilùagbararẹliokun;a osifiináruna
5Aṣkeloniyiorii,yiosibẹru;Gasayiosirii,yiosi banujẹgidigidi,atiEkroni;nitoritiojuyiotìiretirẹ;Ọba yóòsìṣègbéníGásà,akìyóòsìgbéÁṣíkélónì
6ÀgbèrèkanyóòsìgbéníÁṣídódì,èmiyóòsìgéìgbéraga àwọnFílístínìkúrò.
7Emiosimuẹjẹrẹkuroliẹnurẹ,atiohunirirarẹkuro lãrinehinrẹ:ṣugbọnẹnitiobakù,anion,yiojẹtiỌlọrun wa,yiosidabibãlẹJuda,atiEkronibiJebusi
8Emiosidóyiilemikanitoriogun,atinitoriẹnitinkọja lọ,atinitoriẹnitiopada:anianinilarakìyiolàwọnkọja mọ:nitorinisisiyinimotifiojumiri
9Yọgidigidi,iwọọmọbinrinSioni;hó,iwọọmọbinrin Jerusalemu:kiyesii,Ọbarẹmbọwásọdọrẹ:olododolion, osiniigbala;onirẹlẹ,atilorikẹtẹkẹtẹ,atiloriọmọ kẹtẹkẹtẹkantikẹtẹkẹtẹ
Sekariah
10EmiosikekẹkẹkuroniEfraimu,atiẹṣinkuroni Jerusalemu,ọrunogunliaosikekuro:yiosisọalafiasi awọnkeferi:ijọbarẹyiosijẹlatiokundeokun,atilatiodo titideopinaiye.
11Nítiìwọpẹlú,nípaẹjẹmájẹmúrẹnimotiránàwọn ẹlẹwọnrẹjádelátiinúkòtòtíkòsíomi
13NigbatimotifaJudafunmi,timosifiEfraimukún ọrun,timosigbeawọnọmọrẹdide,iwọSioni,siawọn ọmọrẹ,iwọGreece,timosisọọdiidàalagbara
14AosiriOluwalarawọn,ọfàrẹyiosijadelọbi manamana:OluwaỌlọrunyiosifunipè,yiosifiìjigusu lọ.
15Oluwaawọnọmọ-ogunniyiodáàbòbòwọn;nwọnosi jẹ,nwọnositẹwọnbapẹluokutakànakana;nwọnosimu, nwọnosipariwobiẹnitiọti-waini;nwọnosikúnbiọpọn, atibiigunpẹpẹ
16OlúwaỌlọrunwọnyóòsìgbàwọnníọjọnáàgẹgẹbí agboàwọnènìyànrẹ:nítoríwọnyóòdàbíòkútaadé,tía gbésókèbíàsíálóríilẹrẹ
17Nitoripeorerẹtitobito,atibiẹwàrẹtitobito!ọkàyio muinuawọnọdọmọkunrindùn,atiọti-wainititunawọn wundia
ORI10
1ẸbèèrèòjòlọwọOLUWAníàkókòòjòìkẹyìn;bẹni OLUWAyioṣeawọsanmadidán,yiosifunwọnliòjoòjo, funolukulukukorikoninupápa
2Nitoripeawọnoriṣatinsọrọasan,awọnalafọṣẹsitiri eke,nwọnsitirọàláeke;asánniwọnńtùwọnnínú:nítorí náàwọnbáọnàwọnlọbíagboẹran,ìdààmúbáwọn,nítorí pékòsíolùṣọ-àgùntàn
3Ibinumisirusiawọndarandaran,mosijẹawọnewurẹ niya:nitoritiOluwaawọnọmọ-oguntibẹagbo-ẹranrẹwò niileJuda,ositiṣewọnbiẹṣinrererẹliojuogun
4Latiọdọrẹniiguntijadewá,lararẹliiṣotijade,lararẹ liọrunoguntijadewá,lọwọrẹnigbogboaninilaratijade wá
.
6ÈmiyóòsìfúniléJúdàlókun,èmiyóòsìgbailéJósẹfù là,èmiyóòsìmúwọnpadàwásíipòwọn;nitoriemiṣãnu funwọn:nwọnosidabiẹnipeemikòtawọnnù:nitoriemi liOLUWAỌlọrunwọn,emiosigbọtiwọn
7AwọnaraEfraimuyiosidabialagbara,ọkànwọnyiosi yọbitiọti-waini:nitõtọ,awọnọmọwọnyiorii,nwọnosi yọ;ọkànwọnyóòyọnínúOlúwa
8Emiopòsiwọn,emiosikówọnjọ;nitoritimotirà wọnpada:nwọnosipọsiigẹgẹbinwọntinpọsii
9Emiosigbìnwọnlãrinawọnenia:nwọnosirantimini ilẹokere;nwọnosiyèpẹluawọnọmọwọn,nwọnosi pada.
10EmiositunmuwọnpadalatiilẹEgiptiwá,emiosikó wọnjọlatiAssiria;emiosimuwọnwásiilẹGileadiati Lebanoni;akòsìníríàyèfúnwọn
12EmiosifunwọnliokunninuOluwa;nwọnosimarìn sokeatisodoliorukọrẹ,liOluwawi
ORI11
1Ṣíilẹkunrẹsilẹ,iwọLebanoni,kiinákiolejẹigikedari rẹrun.
2Hu,igifiri;nitoriigikedaritiṣubu;nitoritiabaawọn alagbarajẹ:hu,ẹnyinigioakuBaṣani;nítoríigbóàjàràti sÉkalÆ
3Ohùnigbeawọnoluṣọ-agutan;nitoritiabaogowọnjẹ: ohùnigbeawọnẹgbọrọkiniun;nítoríìgbéragaJọdánìti bàjẹ
4BayiliOluwaỌlọrunmiwi;Bọagboẹrantiapa; 5Awọntioniwọnpawọn,tinwọnkòsikàarawọnsi ẹlẹbi:atiawọntintàwọnwipe,OlubukúnliOluwa;nitori tiemiliọlọrọ:awọnoluṣọ-agutanwọnkòsiṣãnufunwọn
6Nitoripeemikìyioṣãnufunawọntingbeilẹnamọ,li Oluwawi:sawòo,emiofiolukulukuenialeọwọẹnikeji rẹ,atileọwọọbarẹ:nwọnosikọlùilẹna,emikìyiosi gbàwọnlọwọwọn
7Emiosibọagbo-ẹranpipa,aniiwọ,talakàagbo-ẹran. Mosimúọpámejifunmi;ọkannimopèBeauty,atiawọn miirannimopèBand;mosìbọagboẹrannáà
8Mokéoluṣọ-agutanmẹtakurolioṣùkan;ọkànmisi korirawọn,ọkànwọnsikoriramipẹlu
9Nigbananimowipe,Emikiyiobọnyin:ẹnitiobakú,jẹ kiokú;atieyitiaokekuro,kiakeekuro;kíàwọnyòókù sìjẹẹranaraẹlòmíràn
10Mosimúọpámi,aniẸwa,mosigéesiwẹwẹ,kiemi kioledàmajẹmumitimotibagbogboeniadá.
11Asifọliọjọna:bẹliawọntalakàagbo-ẹrantiodurodè mimọpe,ọrọOluwani
12Mosiwifunwọnpe,Biẹnyinbarò,ẹfunmiliiyeowomi;atibikobaṣebẹ,faradaBẹninwọnwọnọgbọn owofadakàfunowomi
13OLUWAsiwifunmipe,Sọọsiamọkoko:iyeowo reretiafiṣeyemilọwọwọnMosìmúọgbọnowófàdákà náà,mosìsọwọnsínúamọkòkòníiléOlúwa
14Nigbananimokeọpámikeji,aniẸgbẹ,kiemikiole baẹgbẹaráJudaatiIsraeliká
15OLUWAsiwifunmipe,Tunmuohun-èlooluṣọagutanaṣiweretọọwá.
16Nitorikiyesii,emiogbéoluṣọ-agutankandideniilẹ na,tikìyiobẹawọntiakekuro,tikìyiowáọmọna,tikì yiosimueyitioṣẹsàn,bẹnikìyiobọeyitiodurojẹ: ṣugbọnonojẹẹranọrá,yiosifàẽkawọnya
17Egbenifunoluṣọ-agutanoriṣatiofiagbo-ẹransilẹ!idà yiowàliaparẹ,atiliojuọtúnrẹ:apárẹyiodimimọgbẹ, ojuọtúnrẹyiosiṣokunkunpatapata
ORI12
1ỌRỌỌRỌOluwafunIsraeli,liOluwawi,ẹnitiona ọrun,tiosifiipilẹaiyelelẹ,tiosidaẹmienianinurẹ.
2Kiyesii,EmiosọJerusalemudiagoiwarìrifungbogbo eniayikakiri,nigbatinwọnodótìJudaatiJerusalemu
3Níọjọnáà,nóosọJerusalẹmudiòkútaìnirafúngbogbo eniyan
4Liọjọna,liOluwawi,Emiofiiyanulùolukulukuẹṣin, atiẹnitiogùnuniisinwin:emiosilaojumisiileJuda, emiosifiifọjulùgbogboẹṣinawọnenia
5AwọnbãlẹJudayiosiwiliọkànwọnpe,Awọnolugbe JerusalemuyiojẹagbaramininuOluwaỌlọrunwọn
Sekariah
6LiọjọnaliemioṣeawọnbãlẹJudabiãroinálãrinigi, atibiògùṣọináninuití;nwọnosijẹgbogboawọneniarun yika,liọwọọtúnatiliapaòsi:Jerusalemuliaositungbe niipòrẹ,aniniJerusalemu.
7OlúwayóòkọkọgbaàgọJúdàlà,kíògoiléDáfídìàti ògoàwọnaráJerúsálẹmùmábàagbéarawọngasíJúdà
8LiọjọnaliOluwayiodaboboawọnaraJerusalemu;ẹniti obasiṣeaileraninuwọnliọjọnayiodabiDafidi;Ile DafidiyiosidabiỌlọrun,biangẹliOluwaniwajuwọn
9Yiosiṣeliọjọna,tiemiowálatipagbogboawọnorilẹèderuntiowásiJerusalemu
10Emiosidàẹmiore-ọfẹatiẹbẹsoriileDafidi,atisori awọnaraJerusalemu:nwọnosiwòmitinwọntigúnli ọkọ,nwọnosiṣọfọrẹ,gẹgẹbieniatinṣọfọfunọmọrẹ kanṣoṣo,nwọnosiwànikikorofunu,biẹnitionikikoro funakọbirẹ.
11LiọjọnaliọfọnlayiowàniJerusalemu,gẹgẹbiọfọ HadadrimoniniafonifojiMegidoni
12Ilẹnayiosiṣọfọ,olukulukuidileliọtọ;ìdíléDafidilọtọ, atiàwọnayawọnlọtọ;ìdíléNatanilọtọ,àtiàwọnayawọn lọtọ;
13ÌdíléLefilọtọ,atiàwọnayawọnlọtọ;ìdíléṢimeilọtọ, àtiàwọnayawọnlọtọ;
14Gbogboìdílétíóṣẹkù,ìdílékọọkan,àtiàwọnayawọn lọtọ.
ORI13
1Níọjọnáà,orísunkanyóòṣísílẹfúniléDáfídìàtifún àwọnolùgbéJérúsálẹmùfúnẹṣẹàtifúnàìmọ
2Yiosiṣeliọjọna,liOluwaawọnọmọ-ogunwi,tiemio keorukọawọnoriṣakuroniilẹna,akìyiosirantiwọnmọ: atipẹluemiomukiawọnwoliatiẹmiaimọkiokọjakuro niilẹna.
3Yiosiṣe,nigbatiẹnikanbansọtẹlẹsibẹ,nigbananibaba atiiyarẹtiobíiyiowifunupe,Iwọkiyioyè;nitoritiiwọ nsọrọekeliorukọOluwa:babarẹatiiyarẹtiobiiyiosi gúnuliẹnunigbationsọtẹlẹ
4Yiosiṣeliọjọna,ojuyiotìawọnwoliolukulukulioju iranrẹ,nigbatiobansọtẹlẹ;bẹẹniwọnkògbọdọwọaṣọ lílelátitànwọnjẹ
5Ṣugbọnonowipe,Emikìiṣewoli,agbeliemi;nitori enialiokọmilatipaẹranmọlatiigbaewemiwá.
6Ẹnikanyiosiwifunupe,Ọgbẹkilieyiliọwọrẹ?
Nigbananiyiodahunpe,Awọntiafigbọgbẹminiile awọnọrẹmi.
7Ji,iwọidà,sioluṣọ-agutanmi,atisiọkunrinnatiiṣe ẹlẹgbẹmi,liOluwaawọnọmọ-ogunwi:kọluoluṣọ-agutan, awọnagutanyiosituka:emiosiyiọwọmisiawọnọmọ wẹwẹ
8Yiosiṣe,nigbogboilẹna,liOluwawi,aokeipameji ninurẹkuro,nwọnosikú;ṣugbọnaofiẹkẹtasilẹninurẹ.
9Emiosimuidamẹtalàinájá,emiosiyọwọnmọbiati nyọfadaka,emiosidanwọnwòbiatindanwurawò: nwọnokepèorukọmi,emiosigbọwọn:emiowipe,enia mini:nwọnosiwipe,OluwaliỌlọrunmi
ORI14
1Kiyesii,ọjọOluwambọ,aosipinikogunrẹlãrinrẹ.
2Nitoriemiokógbogboorilẹ-èdejọsiJerusalemufun ogun;aosikóiluna,aosikóilena,atiawọnobinrin;ati
idajiilunayiojadelọsiigbekun,atiiyokùawọneniania kìyiokekuroniilu.
3NigbananiOluwayiojadelọ,yiosibaawọnorilẹ-ède wọnnijà,gẹgẹbinigbatiotijàliọjọogun.
4AtiẹsẹrẹyiosiduroliọjọnaloriòkeOlifi,tiowà niwajuJerusalemuniìhaìla-õrùn,òkeOlifiyiosilẹlãrin rẹsiìhaìla-õrùnatisiiwọ-õrun,afonifojinlakanyiosiwà; ìdajìòkènáàyóòsìṣílọsíìhààríwá,àtiìdajìrẹsíhàgúúsù.
5Ẹnyinosisálọsiafonifojiòke;nítoríàfonífojìàwọnòkè yóòdéÁsálì:nítòótọ,ẹyinyóòsá,gẹgẹbíẹyintisáfún ìṣẹlẹnáàníọjọÙsáyàọbaJúdà:OlúwaỌlọrunmiyóòsì dé,àtigbogboàwọnènìyànmímọpẹlúrẹ
6Yiosiṣeliọjọna,imọlẹkìyiomọ,bẹnikìyioṣokunkun; 7ṢugbọnyiojẹọjọkantiOLUWAyiomọ,kìiṣeọsán, tabioru:ṣugbọnyiosiṣe,liaṣalẹyiojẹimọlẹ
8Yiosiṣeliọjọna,omiìyeyiotijadelatiJerusalemuwá; ìdajìwọnsíhàÒkunìṣáájú,àtiìdajìwọnsíhàÒkunìkọsẹ: níìgbàẹẹrùnàtiníìgbàòtútùyóòrí
9Oluwayiosijọbalorigbogboaiye:liọjọnaliOLUWA kanyiowà,atiorukọrẹkan
10GbogboilẹnáàyóòdàbípẹtẹlẹkanlátiGébàdéRímónì níìhàgúúsùJérúsálẹmù:aósìgbéesókè,aósìmáagbé ibẹ,látiẹnubodèBẹńjámínìtítídéibiẹnubodèàkọkọ,dé ẹnubodèigun,àtilátiiléìṣọHánánélìdéibiìfúntíọba
11Awọneniayiosimagbeinurẹ,kìyiosisiiparun patapatamọ;ṣugbọnJerusalemuniaogbenilailewu 12EyiniyiosijẹàruntiOLUWAyiofikọlùgbogbo awọneniatiotibáJerusalemujà;Ẹranarawọnyóòrun nígbàtíwọnbádúrólóríẹsẹwọn,ojúwọnyóòsìjónánínú ihòwọn,ahọnwọnyóòsìrunníẹnuwọn
13Yiosiṣeliọjọna,ariwonlalatiọdọOluwawáyiowà lãrinwọn;nwọnosidiọwọẹnikejirẹmu,ọwọrẹyiosi didesiọwọẹnikejirẹ
14JudapẹluyiosijàniJerusalemu;atiọrọgbogboawọn keferiyikaliaokojọ,wurà,atifadaka,atiaṣọliọpọlọpọ 15Bẹniàrunẹṣin,ibaka,ibakasiẹ,atitikẹtẹkẹtẹ,atiti gbogboẹrankotiowàninuagọwọnyiyiosiri,gẹgẹbi àrunyi
16Yiosiṣe,olukulukuẹnitiokùninugbogboorilẹ-èdeti owásiJerusalemuyiomagòkelọlatiọdọọdunlatisin Ọba,Oluwaawọnọmọ-ogun,atilatipaajọagọmọ
17Yiosiṣe,ẹnikẹnitikòbagòkewáninugbogboidile aiyesiJerusalemulatisinỌba,Oluwaawọnọmọ-ogun,kì yiorọsoriwọn
18AtibiidileEgiptikòbagòkelọ,tinwọnkòsiwá,tikò siòjo;ajakalẹ-arunnayiowà,tiOLUWAyiofikọlùawọn keferitikògokewálatipaajọagọmọ
19EyiniyiojẹijiyaEgipti,atiiyàgbogboorilẹ-èdetikò gòkewálatipaajọagọmọ
20Liọjọnayiowàloriagogoẹṣin,MIMỌSIOLUWA; àwọnìkòkòtíówàninuiléOLUWAyóodàbíàwọn àwokòtòtíówàníwájúpẹpẹ.
21Nitõtọ,gbogboìkokoniJerusalemuatiniJudaniyiojẹ mimọfunOluwaawọnọmọ-ogun:gbogboawọntinrubọ yiosiwá,nwọnosimuninuwọn,nwọnosisèninurẹ:li ọjọnakìyiosisiaraKenaanimọniileOluwaawọnọmọogun.